Ọ̀jọ̀gbọ́n Ayọ̀ Akínwálé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Ẹ̀ka; fix red category
Ìlà 1: Ìlà 1:
Ọ̀jọ̀gbọ́n '''Ayọ̀ Akínwálé''' jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, olùgbéré jáde ati Olùkọ́ àgbà fásitì.
Ọ̀jọ̀gbọ́n '''Ayọ̀ Akínwálé''' jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, olùgbéré jáde ati Olùkọ́ àgbà fásitì.
==Ìgbésí ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀==
==Ìgbésí ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀==
Wọ́n bí Akínwálé ní Ìlú [[Ìbàdàn]], ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oníwé mẹ́wàá ti Methodist High School àti [[Yunifásitì Ìlú Ìbàdàn]]. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti ìlú Ìbàdàn.<ref name=dawn>{{cite web|url=http://dawncommission.org/professor-ayo-akinwale/|website=Dawn Commission|title=Professor Ayo Akinwale|accessdate=August 29, 2015}}</ref> Ó tún jẹ́ adarí ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Faculty of Arts and Culture ní [[University of Ilorin]].<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |archive-url=https://archive.is/20141115213943/http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Don Tasks Nollywood on Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref><ref>{{cite web | url=http://www.modernghana.com/movie/437/3/lecturers-as-nollywood-stars.html | title=Lecturers as Nollywood Stars | publisher=modernghana.com | accessdate=15 November 2014}}</ref> Ọ̀jọgbọ́n Akínwálé nígbà ayé rẹ̀ tún jẹ́ alága fún ìgbìmọ̀ àwọn oníṣẹ́-ọnà (Council for Artand Culture) ti [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]]. Bákan náà ni ó ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn eré ọdún ìbílẹ̀ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]
Wọ́n bí Akínwálé ní Ìlú [[Ìbàdàn]], ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oníwé mẹ́wàá ti Methodist High School àti [[Yunifásítì ìlú Ìbàdàn]]. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti ìlú Ìbàdàn.<ref name=dawn>{{cite web|url=http://dawncommission.org/professor-ayo-akinwale/|website=Dawn Commission|title=Professor Ayo Akinwale|accessdate=August 29, 2015}}</ref> Ó tún jẹ́ adarí ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Faculty of Arts and Culture ní [[University of Ilorin]].<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |archive-url=https://archive.is/20141115213943/http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Don Tasks Nollywood on Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref><ref>{{cite web | url=http://www.modernghana.com/movie/437/3/lecturers-as-nollywood-stars.html | title=Lecturers as Nollywood Stars | publisher=modernghana.com | accessdate=15 November 2014}}</ref> Ọ̀jọgbọ́n Akínwálé nígbà ayé rẹ̀ tún jẹ́ alága fún ìgbìmọ̀ àwọn oníṣẹ́-ọnà (Council for Artand Culture) ti [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]]. Bákan náà ni ó ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn eré ọdún ìbílẹ̀ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]].
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 1970s níbi tí ó kópa ní àwọn eré sinimá orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti àwọn eré ìtagé mìíràn.<ref name=dawn/> Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánọ́lá ti [[4th Africa Movie Academy Awards]] ẹlẹ́kẹrin irú rẹ̀ níbi tí wọ́n ti yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ọkùnrin tí ó peregedé jùlọ..<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |archive-url=https://archive.is/20141115213942/http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Between Film And Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref>


Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 1970s níbi tí ó kópa ní àwọn eré sinimá orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti àwọn eré ìtagé mìíràn.<ref name=dawn/> Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánọ́lá ti [[4th Africa Movie Academy Awards]] ẹlẹ́kẹrin irú rẹ̀ níbi tí wọ́n ti yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ọkùnrin tí ó peregedé jùlọ..<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |archive-url=https://archive.is/20141115213942/http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Between Film And Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref>


==Àwọn sinimá tí ó ti ṣe==
==Àwọn sinimá tí ó ti ṣe==

Àtúnyẹ̀wò ní 16:45, 15 Oṣù Kẹ̀sán 2020

Ọ̀jọ̀gbọ́n Ayọ̀ Akínwálé jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, olùgbéré jáde ati Olùkọ́ àgbà fásitì.

Ìgbésí ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Akínwálé ní Ìlú Ìbàdàn, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oníwé mẹ́wàá ti Methodist High School àti Yunifásítì ìlú Ìbàdàn. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti ìlú Ìbàdàn.[1] Ó tún jẹ́ adarí ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Faculty of Arts and Culture ní University of Ilorin.[2][3] Ọ̀jọgbọ́n Akínwálé nígbà ayé rẹ̀ tún jẹ́ alága fún ìgbìmọ̀ àwọn oníṣẹ́-ọnà (Council for Artand Culture) ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Bákan náà ni ó ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn eré ọdún ìbílẹ̀ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 1970s níbi tí ó kópa ní àwọn eré sinimá orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti àwọn eré ìtagé mìíràn.[1] Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánọ́lá ti 4th Africa Movie Academy Awards ẹlẹ́kẹrin irú rẹ̀ níbi tí wọ́n ti yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ọkùnrin tí ó peregedé jùlọ..[4]

Àwọn sinimá tí ó ti ṣe

  • Sango (1997)
  • Ladepo Omo Adanwo (2005)
  • Iranse Aje (2007)

Ikú rẹ̀

Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwálé ṣaláìsí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàán ọdún 2020.

Àwọn ìtọ́ka sí

  1. 1.0 1.1 "Professor Ayo Akinwale". Dawn Commission. Retrieved August 29, 2015. 
  2. "Don Tasks Nollywood on Professionalism". thisdaylive.com. Archived from the original on 15 November 2014. Retrieved 15 November 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Lecturers as Nollywood Stars". modernghana.com. Retrieved 15 November 2014. 
  4. "Between Film And Professionalism". thisdaylive.com. Archived from the original on 15 November 2014. Retrieved 15 November 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

Àdàkọ:Authority control