Tutsi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: [[Tutsi] Tutsi jé òkan lárà àwon olùgbé meta àwon ènìyàn orílè èdè Rwanda and Burundi. Ìyàtò díè ló wà láàrìn àsà àwon ará Tutisi ...
 
No edit summary
Ìlà 1: Ìlà 1:
[[Tutsi]
[[Tutsi]]

Tutsi jé òkan lárà àwon olùgbé meta àwon ènìyàn orílè èdè Rwanda and Burundi. Ìyàtò díè ló wà láàrìn àsà àwon ará Tutisi àti Hutu.
Tutsi jé òkan lárà àwon olùgbé meta àwon ènìyàn orílè èdè Rwanda and Burundi. Ìyàtò díè ló wà láàrìn àsà àwon ará Tutisi àti Hutu.

Àtúnyẹ̀wò ní 15:26, 12 Oṣù Kejì 2007

Tutsi

Tutsi jé òkan lárà àwon olùgbé meta àwon ènìyàn orílè èdè Rwanda and Burundi. Ìyàtò díè ló wà láàrìn àsà àwon ará Tutisi àti Hutu.

Àgbè àti Olùsìn maalu ni isé àárò abínibí àwon ara Tutsi. Maálù jé ohun tí àwon ará Tutsi fi máa ń fi agbára àti Olà won han, èyí ló sì mú àwon ará Tutsi jé Olúborí nínú isé àgbè. Fun bí èédégbèta odún séyin ni Tutusi ti ń se ìjoba lórí àwon tókù