Áljẹ́brà onígbọrọ: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 11: Ìlà 11:


[[Category:Ìmọ̀ ìsirò]]
[[Category:Ìmọ̀ ìsirò]]



[[ar:جبر خطي]]
[[ar:جبر خطي]]
[[bn:রৈখিক বীজগণিত]]
[[cs:Lineární algebra]]
[[cs:Lineární algebra]]
[[da:Lineær algebra]]
[[da:Lineær algebra]]
[[de:Lineare Algebra]]
[[de:Lineare Algebra]]
[[en:Linear algebra]]
[[en:Linear algebra]]
[[es:Álgebra lineal]]
[[eo:Lineara algebro]]
[[eo:Lineara algebro]]
[[es:Álgebra lineal]]
[[fa:جبر خطی]]
[[fa:جبر خطی]]
[[fi:Lineaarialgebra]]
[[fr:Algèbre linéaire]]
[[fr:Algèbre linéaire]]
[[he:אלגברה לינארית]]
[[ko:선형대수학]]
[[hu:Lineáris algebra]]
[[id:Aljabar linier]]
[[id:Aljabar linier]]
[[is:Línuleg algebra]]
[[is:Línuleg algebra]]
[[it:Algebra lineare]]
[[it:Algebra lineare]]
[[ja:線型代数学]]
[[he:אלגברה לינארית]]
[[ka:წრფივი ალგებრა]]
[[ka:წრფივი ალგებრა]]
[[ko:선형대수학]]
[[lt:Tiesinė algebra]]
[[lt:Tiesinė algebra]]
[[hu:Lineáris algebra]]
[[nl:Lineaire algebra]]
[[nl:Lineaire algebra]]
[[ja:線型代数学]]
[[no:Lineær algebra]]
[[no:Lineær algebra]]
[[pl:Algebra liniowa]]
[[pl:Algebra liniowa]]
Ìlà 37: Ìlà 38:
[[ro:Algebră liniară]]
[[ro:Algebră liniară]]
[[ru:Линейная алгебра]]
[[ru:Линейная алгебра]]
[[sh:Linearna algebra]]
[[simple:Linear algebra]]
[[simple:Linear algebra]]
[[sl:Linearna algebra]]
[[sl:Linearna algebra]]
[[sr:Линеарна алгебра]]
[[sr:Линеарна алгебра]]
[[sh:Linearna algebra]]
[[fi:Lineaarialgebra]]
[[sv:Linjär algebra]]
[[sv:Linjär algebra]]
[[th:พีชคณิตเชิงเส้น]]
[[th:พีชคณิตเชิงเส้น]]
[[vi:Đại số tuyến tính]]
[[tr:Lineer Cebir]]
[[tr:Lineer Cebir]]
[[ur:لکیری الجبرا]]
[[ur:لکیری الجبرا]]
[[vi:Đại số tuyến tính]]
[[zh:线性代数]]
[[zh:线性代数]]

Àtúnyẹ̀wò ní 14:04, 8 Oṣù Kàrún 2007

Aljebra alatele (linear algebra) je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon atokaona (vector), aaye atokaona (vector space), maapu alatele (linear map) ati awon ona idogba alatele (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi aljebra alatele wulo lopolopo ninu aljebra afoyemo ati agbeyewo alabase (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon sayensi aladabaye ati sayensi awujo nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).

Ìtàn Áljẹ́brà alátẹ̀lé

Itan aljebra ayeodeoni bere ni arin odun 1843 ati 1844. Ni odun 1843, William Rowan Hamilton (eni ti o koko soro nipa atokaona) se awari quaternions. Ni odun 1844, Hermann Grassmann ko iwe ni ede Germani pelu akole Die lineale Ausdehnungslehre. Arthur Cayley mu apotinomba (matrix) wa ni odun 1857. Ilana Cramer to n fihan wa bi a se le s'ojutu awon idogba iseyato abo (partial differential equation) lo so aljebra alatele di eko ti a n ko ni awon ile-eko giga. Fun apere, E.T. Copson ko pe:

Ni odun 1922 ti mo di oluko kekere ni ile-eko giga Edinburgh, o yamilenu lati ri pe ilanaeto eko yato si ti ile-eko giga Oxford. Eka bi isodiodidi Lebesgue (Lebesgue integration), ero apotinomba (matrix theory), agbeyewo aminomba (numerical analysis), alawonile Riemannian (Riemannian geometry), lori awon eyi ti n ko mo nkankan nipa won.... E.T. Copson, Oro Isaju si Idogba Iseyato Abo, 1973