Plánẹ́tì kékeré
Ìrísí
Kini awon Planeti kékeré?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni eto orun awa ni planeti marun. Won yika orun awa n pe awon planeti yii bi gégé jijinna ti orun ti o kékeré si awon planeti ti o tobi ni jijinna: Ceres, Pluto, Haumea, Makemake, ati Eris.[1]