Złoty
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Polish złoty)
Złoty jẹ́ owó tí àwọn ara orilẹ-ede Pólándì[1]ń ná fun gbogbo eto kara-kata wọn. Orilẹ-ede Poland wa ni Kọntinẹnti Europe.
Ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ tí à ń pè ní złoty yi ní èdè Poliṣi dúró fún àpẹrẹ ọkunrin tó dara bi i wura. Orilẹ-ede Pólándì bẹrẹ si ni na owo złoty yii ni ọdun 1924 sugbọn wọn ti bẹrẹ akojade owó naa ni ọjọ́ keji-din-lọgbọn oṣu keji, ọdun 1919.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ American Heritage Dictionary of the English Language, 3rd ed., p. 2078. ^