Project 211
Àdàkọ:History of the People's Republic of China Project 211 (Àdàkọ:Zh) ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1995 tí ó jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe tí óbdá lórí àwọ Fásitì tí wọ́n ṣe pàtàkì ní orílẹ̀-èdè China lábẹ́ àjọ tí ó bójútó ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé. Wọ́n da iṣẹ́ àkànṣe yí sílẹ̀ láti lè fi ẹsẹ̀ iṣẹ́ ìwádí tó peregedé múlẹ̀ kí wọ́n sì wá àwọn ọ̀nà tó yanrantí fún ìdàgbà-sókè àwùjọ. Nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, láàrín ọdún 1996 sí ọdún 2000, iye owó tí wọ́n ṣamúlò lápapọ̀ jẹ́ bílíọ́nù méjì Dólà.[1] Nígbà tí yóò fi di ọdún 2008, orílẹ̀-èdè China ti ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí ó ti tó 116 nígbà tí ìdá mẹ́fà nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ náà ti wà ní ipò tí wọ́n fẹ́ gan an. Project 11 mú kíkọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìwòsàn onípele keji àti onípele kẹta lọ sí ìlú òkèrè láti lọ kọ́ nípa ìmọ̀ náà siwájú si. Ilé-iṣẹ́ ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé yí ń ri dájú wípé wọ́n ṣe àmúlò 85% àwọn ẹ̀kọ́ tí ó ṣe pàtàkì sí wọn, nígbà tí wọ́ sì wọ́ ṣe àmúlò %96 iyará ìwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, wọ́n sì owó tí ó tó ìdá %70 sí ètò ìwádí ìmọ̀ ìjànlẹ̀ nìkanef>Over 10 billion yuan to be invested in "211 Project" - People's Daily Online Archived 2008-04-28 at the Wayback Machine.</ref> Gẹ́gẹ́ bí Academic Ranking of World Universities àti Times Higher Education World University Rankings ṣe Sọ, púpọ̀ nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí Project 211 da sílẹ̀ ni wọ́n wà ní òkè jùlọ nínú àtòjọ ọgọ́rùn ún akọ́kọ́ nínú àtòjọ wọn.[2][3] Orúkọ iṣẹ́ àkànṣe yí ni wọ́ fà yọ látara gbólóhùn yí: "面向21世纪,办好100所高校 tí ó túmọ̀ sí : (Gbí gbaradì fún sẹ́túrì kọkànlélógún). Gbogbo fásitì tí wọ́ súgbá ètò yí jẹ́ ọgọ́rùn ún kan.[4] Láti ọdún 2014, Project 211 ni wọ́n ti ń ṣàtúntò sí tí wọ́n sì ti fi ìṣeẹ́ àkànṣe míràn tí wọ́n pe ní Plan 111 tí yóò ma ṣe àfikún ọgbọ́n orí àti ìwà ọmọlúàbí kún iṣẹ́ àkànṣe náà.[5][6] Nínú oṣù kẹsàn an ọdún 2017, wọ́n tún ṣe agbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe míràn tí wọ́n pe ní Double First Class University Plan was announced.[7][8] Agbékalẹ̀ tuntun yí kò fi bẹ́ẹ̀ ye àjọ tí wọ́n rí sí ipò tí àwọn fásitì kọ̀ọ̀kan wà lágbàáyé bí wọ́n ṣe lè ṣe ìgbéléwọ̀n fún wọn.[7] or replaces Project 211 and Project 985.[8]
Àtòjọ àwọn fásitì náà nìyí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ lè wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Project 985
- 863 Program
- Chinese university ranking (Chinese Academy of Management Science)
- Rankings of universities in China
- List of universities in China
- Science and technology in China
- C9 League
- Excellence League
- Double First Class University
Àwọn itọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Li Lixu (2004). "China’s Higher Education Reform 1998-2003: A Summary". Asia Pacific Education Review V (1): 14–22. http://eri.snu.ac.kr/aper/pdf/Vol%205%20No%201%20July%202004%20PDF/02.Li%20Lixu.pdf.
- ↑ "World University Rankings". Times Higher Education (THE) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-20. Retrieved 2020-05-05.
- ↑ "ARWU World University Rankings 2019 | Academic Ranking of World Universities 2019 | Top 1000 universities | Shanghai Ranking - 2019". www.shanghairanking.com. Archived from the original on 2019-08-15. Retrieved 2020-05-05.
- ↑ ""211工程"大事记". Ministry of Education, PRC (in Edè Ṣáínà). Archived from the original on November 22, 2016. Retrieved March 8, 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2017-09-09. Retrieved 2017-09-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) 南京有高校称“211建设”已暂停 - ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2017-09-09. Retrieved 2017-09-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) 985、211取消后 仅88所高校入选“111计划”(名单) - ↑ 7.0 7.1 "China to develop 42 world-class universities". People's Daily. 21 September 2017. http://en.people.cn/n3/2017/0921/c90000-9272101.html.
- ↑ 8.0 8.1 "双一流大学 (shuāngyīliú dàxué): Double top university plan". Archived from the original on 2017-09-25. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Ìtàkùn àsopọ̀ Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Project 211: the 106 universities and colleges (the webpage written in Simple Chinese)
- Ministry of Education 211 Project
Àdàkọ:Project 211 Àdàkọ:Project 985 Àdàkọ:Education of the People's Republic of China