Ìṣeìjọánglíkánì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1: Ìlà 1:
'''Ìṣeìjọánglíkánì''' ('''Anglicanism''') je asa kan ninu [[Christianity|Esin Kristi]] to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo [[Church of England|Ijo ile Ilegeesi]] tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.<ref name="cofe">{{cite web| url=http://www.cofe.anglican.org/faith/anglican/ | title=What it means to be an Anglican | Church of England | accessdate=2009-03-16}}</ref> Oro ''Anglikani'' wa lati inu ''ecclesia anglicana'', oro inu ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi ''Ijo Ilegeesi (the English Church)''. Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje ''Awon Anglikani''. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara [[Anglican Communion|Idarapo awon Anglikani]] kariaye.<ref name="acomm">{{cite web| url=http://www.anglicancommunion.org/ | title=The Anglican Communion official website - homepage | accessdate=2009-03-16}}</ref>
'''Ìṣeìjọánglíkánì''' ('''Anglicanism''') je asa kan ninu [[Christianity|Esin Kristi]] to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo [[Church of England|Ijo ile Ilegeesi]] tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.<ref name="cofe">{{cite web| url=http://www.cofe.anglican.org/faith/anglican/ | title=What it means to be an Anglican | Church of England | accessdate=2009-03-16}}</ref> ''Anglikani'' bi oro wa lati inu ''ecclesia anglicana'', oro ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi ''Ijo Ilegeesi (the English Church)''. Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje ''Awon Anglikani''. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara [[Anglican Communion|Idarapo awon Anglikani]] kariaye.<ref name="acomm">{{cite web| url=http://www.anglicancommunion.org/ | title=The Anglican Communion official website - homepage | accessdate=2009-03-16}}</ref>





Àtúnyẹ̀wò ní 12:25, 27 Oṣù Kejìlá 2010

Ìṣeìjọánglíkánì (Anglicanism) je asa kan ninu Esin Kristi to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo Ijo ile Ilegeesi tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.[1] Anglikani bi oro wa lati inu ecclesia anglicana, oro ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi Ijo Ilegeesi (the English Church). Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje Awon Anglikani. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara Idarapo awon Anglikani kariaye.[2]




Itokasi

  1. "What it means to be an Anglican". Retrieved 2009-03-16.  Text " Church of England " ignored (help)
  2. "The Anglican Communion official website - homepage". Retrieved 2009-03-16.