Mwai Kibaki: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: Mwai Kibaki A bí Kìbákì ní ojókèèédógún osù kókànlá odún 1931 Orúko ìbatisi rè ni Emilio Stanley sùgbón kò pé tí ó fi or...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 12:24, 8 Oṣù Kejì 2008

Mwai Kibaki

A bí Kìbákì ní ojókèèédógún osù kókànlá odún 1931 Orúko ìbatisi rè ni Emilio Stanley sùgbón kò pé tí ó fi orúko yìí sílè tí ó n jé orúko kìkúyí. Òjísé Olórun kan ara Ítálì ni ó sà á lámì. Omo ìjo Àgùdà (Catholic) ni Kìbákì. History àti Political Science ni ó kà ní Màkéréré University ní Kampala, Uganda. Òun ni ó s eipò kìíní nínú kíláàsì rè nígbà tí ó jáde ní 1955. Ó fi èkó-òfè lo London School of Economics níbi tí ó ti ka Public finance tí ó sì gboye B.Sc ní 1959. Ó pada sí makerere. Ó se isé olùkó díè kí ó tó fi isé náà sílè lo máa se òsèlú. Ó gbé àpótí ó wolé sí ilé asòfin. Wón jo dá egbé Kenya African National Union (KANU) sílè ni ní 1960 Léyìn odún méjì tí ó ti wà nílé asòfin,wón so ó di Minister of Commerce and Industry. Nígbà tí Arap Moi di àre léyìn ikú Jomo Kenyatta ní 1978, ó di igbá kejì àre. Ní odún 1990, ó dá egbé tirè tí ó n jé Democratic Party sílè Ní odún 2002, ó di àre Kenya.