Felix Ohiwerei: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: [Chiwerri, Felix Omoikhoje Aizobeoje ]] A bí i ní 18th January, 1936 ní Owan ní ìpínlè Edó ní ilè Nààjíríà. Ó lo sí ilé-èkó ní St David’s School A...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 12:29, 8 Oṣù Kejì 2008

[Chiwerri, Felix Omoikhoje Aizobeoje ]]

A bí i ní 18th January, 1936 ní Owan ní ìpínlè Edó ní ilè Nààjíríà. Ó lo sí ilé-èkó ní St David’s School Arbiosi ni 1944-1946; Government School, Owerri 1947-1950, Government Secondary School, owerri 1951-1955; Nigerian College of Arts, Science and Technology 1956-1958; University College (tí ó ti di University of Ibadan) Ibadan 1958-1961; Ó dara pò mo Nigerian Breweries ní 1962 gégé bí i manager tí ó wà lénu ìkósé. Ó bèrè isé ó sì bèrè síí ní ìgbéga títí tí ó fi di Chairman àti Chief Executive officer ilé-isé náà ní 1997. Ó di se a laja Lever Brothers Plc (tí ó di di Unilever), ó se alága virgin Anline . Ó jé fellow Nigerian Marketing Association (NMA), Geographical fcuty of Nigeria, Institute of Directors àti Adverlising Practitioners of Nigeria.