Baháí: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: [Bahai ]] ==Bahai== Èsìn kan tí wón dá sílè ní odún 1863 tí ó n mú gbogbo èyí tí ó dára lára èsìn mìíran lò tí ó sì n mú kí gbogbo àwon ...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 10:42, 29 Oṣù Kejì 2008

[Bahai ]]

Bahai

Èsìn kan tí wón dá sílè ní odún 1863 tí ó n mú gbogbo èyí tí ó dára lára èsìn mìíran lò tí ó sì n mú kí gbogbo àwon ènìyàn ayé para pò. Àwon tí ó n sin èsìn yìí ni wón n pè ní Bahais.


Assegai

[[Assegai]

Orísìí òkò kan tí ó kúrú tí enu rè jé irin tí wón fi máa n sode ní South Africa.

Atlantic

Atlantic

Omi òkun. Ó tóbi gan-an ni. Ó wà láàrin Àméríkà àti Aáfíríkà.

Átíláàsì

Atilaasi

Ìwé tí wón ya àwòrún orílè-èdè sí.