Mohammed Yunus: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: Mohammed Yunus Omo ilè Bangladesh ni Mohammed Yunus. Wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní Chittagong. Gosimíìtì ni bàbá rè. Ìyá rè jé Sofi...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 15:51, 6 Oṣù Kẹta 2008

Mohammed Yunus

Omo ilè Bangladesh ni Mohammed Yunus. Wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní Chittagong. Gosimíìtì ni bàbá rè. Ìyá rè jé Sofia Khatun. Mama rè yìí máa n ran àwon òtòsì lówó. Ìwà yìí sì ran Mohammed. Nígbà tí òun náà dàgbà, ó dí ilé-ìfowópamó tí a ti lè máa yá àwon òtòsì lówó sílè. Won kò nílò láti ní ìdúró kankan. Irú bánkì yìí ni í wá di community Bank lóde òní Mohammed Yunus ló kókó dá a sílè. Yunus tí ní irú bánkì yìí nínú abúlé tó tó 35,000 nínú abúlé 68,000 tí ó wà ní Bangladesh. Ó ti yá òpòlopò ènìyán kówó. Obìnrin ló pò jù nínú àwon tí ó n yáwó lówó rè. Òun ni ó gba Nobel Peace Prize fún 2006