Godwin Babátúnde Kofi Akran: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New page: OBA GODWIN BABÁTÚNDE KOFI AKRAN A bí Oba Akran ní ojó kokànlá osù késàn-án odún 1936. Ó lo sí Salvation Army School, Kakawa, Lagos láàrin 19...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 15:12, 14 Oṣù Kẹta 2008

OBA GODWIN BABÁTÚNDE KOFI AKRAN

A bí Oba Akran ní ojó kokànlá osù késàn-án odún 1936. Ó lo sí Salvation Army School, Kakawa, Lagos láàrin 1946 sí 1947, Methodist School, Badagry àti Methodist Teachers Training College, Ìfàkì-Èkìtì láàrin 1956 sí 1957. Ó lo sí International Press Institute, University of East Africa, Nairobi, Kenya ní 1977. Ó di reporter fún West African Plot ní 1961, News Editor, New Nigerian Newspapers 1975-1977. Ó di Oba ìlú Badagry gégé bíi Whemu Aholu Menu Toyi 1 ní odún 1977.