Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k r2.7.1) (Bot: Ìyọkúrò ks:राष्‍ट्रिय गीत
k r2.7.1) (Bot: Ìfikún or:ଜାତୀୟ ସଙ୍ଗୀତ
Ìlà 87: Ìlà 87:
[[nrm:Antienne]]
[[nrm:Antienne]]
[[oc:Imne nacional]]
[[oc:Imne nacional]]
[[or:ଜାତୀୟ ସଙ୍ଗୀତ]]
[[pap:Himno nacional di Aruba]]
[[pap:Himno nacional di Aruba]]
[[pl:Hymn państwowy]]
[[pl:Hymn państwowy]]

Àtúnyẹ̀wò ní 14:36, 17 Oṣù Kejì 2012

Èyí ni orin tí orílè-ède kan máa n ko nígbà tí wón bá n se ayeye. Wón máa n ko ó tí olórí orílè-èdè mìíràn bá wá bè wón wò. Wón máa n ko ó níbi tí àwon ènìyàn bá pé jo sí tàbí ibi òsèlú tó bá se pàtàkì. Enìkan lè dá a ko fún gbogbo ènìyàn tàbí kí gbogbo ènìyàn kópa níní kíko rè.

Òrò inú orin yìí máa n yin orílè-èdè àti àwon ènìyàn tí ó wà nínú rè. Orin yìí máa n sábàá so àwon ohun ribiribi tí ilè kan ti gbé se. Bouget de I’Isle ni ó ko orin ti ilè Faranse ní àsìkò ogun ní 1792. Francis Scott Key ni o ko ti ilè Àmérìkà ní 1814. A kò mo eni tí ó ko ‘God save the Queen’ ti ilè Gèésì sùgbón 1745 ni wón kókó ko ó. ‘Arise, O Compatriots’ ni ó bèrè orin orílè-èdè Nàìjíríà tí a n lò lówólówó báyìí.


Itokasi