Èdè Arméníà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
EmausBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.2+) (Bot: Ìtúnṣe ur:آرمینیائی زبان
Ìlà 131: Ìlà 131:
[[ug:ئەرمەن تىلى]]
[[ug:ئەرمەن تىلى]]
[[uk:Вірменська мова]]
[[uk:Вірменська мова]]
[[ur:آرمینیائی]]
[[ur:آرمینیائی زبان]]
[[vi:Tiếng Armenia]]
[[vi:Tiếng Armenia]]
[[wa:Årmenyin]]
[[wa:Årmenyin]]

Àtúnyẹ̀wò ní 10:36, 23 Oṣù Kàrún 2012

Armenian
Հայերեն Hayeren
Sísọ níArmenia, Russia, Iran, France, Lebanon, Syria, Georgia, Canada, United States
Nagorno-Karabakh (not recognized internationally)
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀6.7 million [1]
Èdè ìbátan
Indo-European
  • Armenian
Sístẹ́mù ìkọArmenian alphabet
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní Armenia
 Nagorno-Karabakh Republic
(internationally unrecognised)
Minority language:[2]
Àdàkọ:CYP
Àkóso lọ́wọ́National Academy of Sciences of Armenia
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1hy
ISO 639-2arm (B)
hye (T)
ISO 639-3variously:
hye – Modern Armenian
xcl – Classical Armenian
axm – Middle Armenian

Èdè Arméníà je ikan lara èdè Indo-European (Indo-Ùrópóàànù) kan ni eléyìí. Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù méje. Àwon tí ó ń so ó ní orílè-èdè Armenia jé mílíònù méta àti egbèrún méfà (3.6 million). Wón tún ń so ó ní Turkish Armenia. Àwon tí ó lo se àtìpó ní Europe (Úróòpù), Àméríkà (USA) àti ààrin gbungbun ìlà-oòrùn àgbáyé (Middle East) náà ń so èdè náà.

Èdè Armenia àtijó (Classical Armenian tí wón ń pè ní Grabar ni wón kókó fi ko lítírésò sílè ní gbogbo àgbáyé. Wón ko ó ní nnkan bíi séńtúrì karùn-ún léyìn ikú Jéésù Kirisitì. Èdè Grabar yìí ni won ń lò gégé bí èdè èsìn fún àwon ijo ilè Armenia òde òní,

Létà álúfábéètì méjìdínlógòjì ni wón fi ń ko èdè yìí sílè. St Mesrop ni ó sèdá álúfábéètì yìí.

Orísìí méjì ni èyà èdè yìí ni ayé òde òní. Òkan nit i apá Ìlà oòrùn tí wón gbé lé orí èka-èdè tí wón ń so ní, ìpínlè Yeravan. Òun ni wón ń lò ní orílè-èdè Armenia. Èkejì nit i Ìwò-oòrùn tí wón gbé lé orí èka-èdè tí wón ń so ní Islanbul. Eléyìí ni wón ń so ní orílè-èdè Turkey.



Itokasi