Ògún (Ọdúnjọ): Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
New page: AWON ÒRÌSÀ TI YORUBA NSÌN (1) Ògún (2) Oríkì Ògún Onírè (3) Sòpònnó (4) Songó Olúkòso (1) Ògún Òrìsà ti o je aláàb...
 
k Poarps ṣeyípòdà ojúewé Ogun (Odunjo)Ògún (Ọdúnjọ)
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 12:57, 27 Oṣù Kẹjọ 2012

AWON ÒRÌSÀ TI YORUBA NSÌN

(1) Ògún

(2) Oríkì Ògún Onírè

(3) Sòpònnó

(4) Songó Olúkòso

(1) Ògún

Òrìsà ti o je aláàbò fun àwon ti o nse ise ogun jíjà, awon olóde, ati awon alágbède ni Ògún; irin isé rè sin i ohunkóhun ti a ba fi irin se. Nitorináà, gbogbo awon ti o ba nfi ohun ti a fi irin se sise wà labe ààbo rè pelu. Fun àpeere, awon ti o nfi áàké tabi ayùn gé igi; awon gbénàgbénà ati awon ti o nrán aso; awon ti o ti kolà ati awon ti o nrán awo; awon ti o nwa okò ilè, ati awon ti o nlu irin; gbogbo awon wonyi gba Ògún bio asíwájú ati aláàbò won; nwon a si maa bè pe ki o máà je ki nwon rí ìpalára ninu isé won....

J.F. Odunjo (1969), Eko Ijinle Yoruba Alawiye, Fun Awon Ile Eko Giga, Apa Keji, Longmans of Nigeria, Ojú-ìwé 88-94.