Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k r2.7.3) (Bot: Ìfikún da:Yoruba
k r2.7.3) (Bot: Ìtúnṣe tr:Yorubalar
Ìlà 75: Ìlà 75:
[[sr:Јоруба]]
[[sr:Јоруба]]
[[sv:Yoruba (folk)]]
[[sv:Yoruba (folk)]]
[[tr:Yoruba]]
[[tr:Yorubalar]]
[[uk:Йоруба (народ)]]
[[uk:Йоруба (народ)]]
[[zh:约鲁巴人]]
[[zh:约鲁巴人]]

Àtúnyẹ̀wò ní 16:58, 28 Oṣù Kẹ̀wá 2012

Yoruba
Kwara State drummers.
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
Over 30 million (est.)[1]
Regions with significant populations
Nàìjíríà Nàìjíríà 29,039,480 [2]
 Benin 1,009,207+ [3]
 Ghana 350,000 [4]
 Togo 85,000 [5]
USA USA
 United Kingdom
Èdè

Yoruba, Yoruboid languages

Ẹ̀sìn

Christianity 60%, Islam 30%, Orisha veneration and Ifá 10%.

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Bini, Nupe, Igala, Itsekiri, Ebira

Awon omo Yoruba ti a pe ni eniyan Yoruba ni ibi yii po gan-an ni. Ile Yoruba ni pupo ninu won wa ni ipinle Edo, Ekiti, Eko, Kwara, Kogi Ogun, Ondo, Osun, Oyo; atiwipe omo Yoruba wa ni Bene (Dahomi), Saro (Sierra Leone) ati Togo, Brazil, Cuba, Haiti,U.S.A. ati Venezuela. Awon Yoruba ni won se ipo keta ni pipo ni ile Naijiria.

Awon Yoruba je awon eniyan kan ti ede won pin si orisirisi. Awon ipin yii ni a nri; a maa lo ipin ede lati fi pe'ede wa ti nse bi ti "americas"; "ekiti"; "eko"; "ijebu"; "ijesha"; "ikale"; "oyo"; ati bebe lo. Laarin eyi, la sii tun ni ede ifo ti nse apere ede to nipin si awon ipin ede ti o po. Yoruba je eniyan kan ti o feran lati maa se aajo. Yoruba a maa nife omo enikeji re.