Èdè Áfríkáánì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Ìlà 63: Ìlà 63:
[[gl:Lingua africáner]]
[[gl:Lingua africáner]]
[[he:אפריקאנס]]
[[he:אפריקאנס]]
[[hi:अफ़्रीकाँस भाषा]]
[[hi:अफ़्रीकांस भाषा]]
[[hif:Afrikaans bhasa]]
[[hif:Afrikaans bhasa]]
[[hr:Afrikaans]]
[[hr:Afrikaans]]

Àtúnyẹ̀wò ní 11:48, 3 Oṣù Kejìlá 2012

Afrikaans
Sísọ níGúúsù ÁfríkàSouth Africa
NamibiaNamibia
BòtswánàBotswana
Lèsóthò Lesotho
SwazilandSwaziland
AgbègbèSouthern Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀est. 6.45 million (first language)
6.75 million (second or third language)
12 to 16 million (basic language knowledge) estimation October 2007[citation needed].
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ níGúúsù ÁfríkàSouth Africa
Àkóso lọ́wọ́Die Taalkommissie
(The Language Commission of the South African Academy for Science and Arts)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1af
ISO 639-2afr
ISO 639-3afr

Àdàkọ:Wiktionary Èdè ìwò oòrùn Jámìnì (a West Germany language) tí ó wáyé láti ara Dóòjì (Dutuh) ni eléyìí tí wón ń so ní Gúsù Aáfíríkà. Àwon tí ó ń so ó tó míhíònù méfà. Wón ń so ó ní Nàmíbíà, màláwì, Zambia àti Zimbabwe. Àwon kan tí ó sì ti se àtìpó lo sí ilè Australia àti Canada náà ń so èdè náà. Wón tún máa ń pa èdè yìí ni kéépú Doòjì (lapa Dutch). Èdè àwon tí ó wá te ilè Gúsù Aáfíríkà dó ní séńtúrì ketàdínlógún (17th century) ni sùgbón ó ti wá yàtò sí èdè Dóòjì (Dutch) ti ilè Úroòpù (Europe) báyìí nítorí èdè àdúgbò kòòkan ti ń wo inú rè. Èdè yìí ni èdè tí ó lé ní ìdajì àwon funfun tí ó dó sí Gúsù Aáfíríkà ń so. Ìdá àádósà n-án àwon tí òbí won jé èyà méjì ni ó sì ń so èdè yìí pèlú. Láti odún 1925 ni won ti ń lo èdè yìí pèlú èdè Gèésì gégé bí èdè ìjoba. Èdè yìí tin í lítírésò. Àkotó Rómáànù ni wón fi ń ko ó.