Allah: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
EmausBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.3) (Bot: Ìyọkúrò mt:Alla
Ìlà 70: Ìlà 70:
[[mrj:Аллах]]
[[mrj:Аллах]]
[[ms:Allah]]
[[ms:Allah]]
[[mt:Alla]]
[[nds-nl:Allah]]
[[nds-nl:Allah]]
[[nl:Allah]]
[[nl:Allah]]

Àtúnyẹ̀wò ní 04:52, 14 Oṣù Kínní 2013

Fáìlì:Allah-eser2.png
Oruko Allāh je kiko ni kaligrafi Arabiki latowo onisona oruudun 17 ara Ottomani Hâfız Osman

Allah (Lárúbáwá: اللهAllāh, IPA: [ʔalˤːɑːh]  ( listen)) ni oro fun Olorun ni ede Arabiki.[1] Botilejepe a mo nibo miran bi oro awon musulumu fun Olorun, oro yi gbogbo na ni awon Arabu yioku onigbagbo Abrahamu unlo fun "Olorun", awon bi Mizrahi Jews, Baha'is ati Eastern Orthodox Christians.[1][2][3] Oro yi na tun ni awon keferi ara Meka na tu lo fun olorun-eleda, o seese ko je orisa igba na ni Arabia akosiwaju-Imale.[4][5]



Itokasi

  1. 1.0 1.1 "Allah." Encyclopædia Britannica. 2007. Encyclopædia Britannica
  2. Encyclopedia of the Modern Middle East and North Africa, Allah
  3. Columbia Encyclopedia, Allah
  4. L. Gardet, "Allah", Encyclopedia of Islam
  5. Smith, Peter (2000). "prayer". A concise encyclopedia of the Bahá'í Faith. Oxford: Oneworld Publications. pp. 274–275. ISBN 1-85168-184-1.