Didius Julianus: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
EmausBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.2+) (Bot: Ìfikún bs:Didije Julijan
k Bot: Ìfikún oc:Didius Julianus
Ìlà 66: Ìlà 66:
[[nl:Didius Julianus]]
[[nl:Didius Julianus]]
[[no:Didius Julianus]]
[[no:Didius Julianus]]
[[oc:Didius Julianus]]
[[pl:Didiusz Julianus]]
[[pl:Didiusz Julianus]]
[[pt:Dídio Juliano]]
[[pt:Dídio Juliano]]

Àtúnyẹ̀wò ní 22:47, 22 Oṣù Kínní 2013

Didius Julianus
20th Emperor of the Roman Empire
Orí-ìtẹ́28 March – 1 June 193
OrúkọMarcus Didius Severus Julianus
(from birth to accession);
Caesar Marcus Didius Severus Julianus Augustus (as emperor)
AṣájúPertinax
Arọ́pọ̀Septimius Severus
Consort toManlia Scantilla
ỌmọDidia Clara
ẸbíajọbaNone
BàbáQuintus Petronius Didius Severus
ÌyáAemilia Clara

Didius Julianus (Látìnì: Marcus Didius Severus Julianus Augustus;[1] 30 January 133 tabi 2 February 137 – 1 June 193), je Obaluaye Romu fun osu meta ni odun 193. O gun ori ite leyin ti o ti fowo ra latowo awon Eso Praetoria, leyin ti awon wonyi ti sekupa asaju re Pertinax. Eyi lo fa Ogun Abele Romu 193–197 wa. Julianus je lile kuro lori ite, o si bo sowo iku latowo aropo re, Septimius Severus.



Itokasi

  1. In Classical Latin, Julianus' name would be inscribed as MARCVS DIDIVS IVLIANVS AVGVSTVS.