Òbìrípo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k robot Adding: sl:Krožnica Removing: ca:Cercle, lv:Riņķis
k robot Adding: ca:CircumferènciaModifying: es:Circunferencia
Ìlà 45: Ìlà 45:
[[bg:Окръжност]]
[[bg:Окръжност]]
[[bn:বৃত্ত]]
[[bn:বৃত্ত]]
[[ca:Circumferència]]
[[cs:Kružnice]]
[[cs:Kružnice]]
[[cv:Çавракăш]]
[[cv:Çавракăш]]
Ìlà 53: Ìlà 54:
[[en:Circle]]
[[en:Circle]]
[[eo:Cirklo]]
[[eo:Cirklo]]
[[es:Círculo]]
[[es:Circunferencia]]
[[et:Ringjoon]]
[[et:Ringjoon]]
[[eu:Zirkulu]]
[[eu:Zirkulu]]

Àtúnyẹ̀wò ní 20:06, 28 Oṣù Kẹfà 2009

Obíríkítí tabi Ìyípo (Circle) pelu arin C ati ilatotan r, je irisi aniwonile to je akojopo awon ojuami ati ijinasi won si arin ti a n pe ni ilatotan (radius).

Iyipo je Ila-alajapo (curve)ti o ti; ti o si pin pepe si apa inu ati ode. Ibu re ni a mo si ayika (circumference). Inu re ni a n pe ni abọ́ (disk). Ọfà (arc) si ni apa iwapapo pato kan lori iyipo na.

Agbeyewo

Idogba fun iyipo

Ti a ba ni ona ipoidojuko x-y, iyipo to ni arin ni (a, b) ati ilatotan r je akojopo gbogbo ojuami (x, y) to fi je pe

Ti o ba je pe ni ojuibere (0, 0) (origin) ni arin re wa, a le so afise dero bayi,


Be si ni tangenti yio je


nigbati , si je ipoidojuko ojuami kanna won.


(xy)