Karl Marx: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Legobot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q9061 (translate me)
k Bot: Ìdípò ìkọ̀rọ̀ oníaraẹni (-],[ +], [)
Ìlà 20: Ìlà 20:
|main_interests = [[Politics]], [[Economics]], [[Philosophy]], [[Sociology]], [[class struggle]], [[History]],
|main_interests = [[Politics]], [[Economics]], [[Philosophy]], [[Sociology]], [[class struggle]], [[History]],
|influences = [[Baruch Spinoza|Spinoza]], [[Immanuel Kant|Kant]], [[Georg Wilhelm Friedrich Hegel|Hegel]], [[Ludwig Feuerbach|Feuerbach]], [[Max Stirner|Stirner]], [[Adam Smith|Smith]], [[Voltaire]], [[David Ricardo|Ricardo]], [[Giambattista Vico|Vico]], [[Jean-Jacques Rousseau|Rousseau]], [[Johann Wolfgang von Goethe|Goethe]], [[Shakespeare]], [[Dante Alighieri|Dante]], [[Charles Fourier|Fourier]],[[Nicolae Balcescu|Balcescu]]
|influences = [[Baruch Spinoza|Spinoza]], [[Immanuel Kant|Kant]], [[Georg Wilhelm Friedrich Hegel|Hegel]], [[Ludwig Feuerbach|Feuerbach]], [[Max Stirner|Stirner]], [[Adam Smith|Smith]], [[Voltaire]], [[David Ricardo|Ricardo]], [[Giambattista Vico|Vico]], [[Jean-Jacques Rousseau|Rousseau]], [[Johann Wolfgang von Goethe|Goethe]], [[Shakespeare]], [[Dante Alighieri|Dante]], [[Charles Fourier|Fourier]], [[Nicolae Balcescu|Balcescu]]
|influenced = [[Mikhail Bakunin|Bakunin]], [[Rosa Luxemburg|Luxemburg]], [[Vladimir Lenin|Lenin]], [[Joseph Stalin|Stalin]], [[Leon Trotsky|Trotsky]], [[Mao Zedong|Mao]], [[Fidel Castro|Castro]], [[Che Guevara|Guevara]], [[György Lukács|Lukács]], [[Antonio Gramsci|Gramsci]], [[Karl Korsch|Korsch]], [[Hannah Arendt|Arendt]], [[Jean-Paul Sartre|Sartre]], [[Simone De Beauvoir]], [[Jean Francois Lyotard]], [[Michel Foucault]], [[Guy Debord|Debord]], [[Frankfurt School]], [[Antonio Negri|Negri]], [[Michael Taussig|Taussig]], [[Manabendra Nath Roy|Roy]], [[Murray Bookchin|Bookchin]] and <small>[[List of Marxists|many more...]]</small>
|influenced = [[Mikhail Bakunin|Bakunin]], [[Rosa Luxemburg|Luxemburg]], [[Vladimir Lenin|Lenin]], [[Joseph Stalin|Stalin]], [[Leon Trotsky|Trotsky]], [[Mao Zedong|Mao]], [[Fidel Castro|Castro]], [[Che Guevara|Guevara]], [[György Lukács|Lukács]], [[Antonio Gramsci|Gramsci]], [[Karl Korsch|Korsch]], [[Hannah Arendt|Arendt]], [[Jean-Paul Sartre|Sartre]], [[Simone De Beauvoir]], [[Jean Francois Lyotard]], [[Michel Foucault]], [[Guy Debord|Debord]], [[Frankfurt School]], [[Antonio Negri|Negri]], [[Michael Taussig|Taussig]], [[Manabendra Nath Roy|Roy]], [[Murray Bookchin|Bookchin]] and <small>[[List of Marxists|many more...]]</small>
|notable_ideas = Co-founder of [[Marxism]] (with [[Friedrich Engels|Engels]]), [[surplus value|the Theory of Surplus Value]], [[Marx's theory of alienation|alienation]] and exploitation of the worker, ''[[The Communist Manifesto]],'' ''[[Das Kapital]],'' [[Historical materialism|Materialist conception of history]] |}}
|notable_ideas = Co-founder of [[Marxism]] (with [[Friedrich Engels|Engels]]), [[surplus value|the Theory of Surplus Value]], [[Marx's theory of alienation|alienation]] and exploitation of the worker, ''[[The Communist Manifesto]],'' ''[[Das Kapital]],'' [[Historical materialism|Materialist conception of history]] |}}

Àtúnyẹ̀wò ní 15:26, 11 Oṣù Kàrún 2013

Karl Heinrich Marx
OrúkọKarl Heinrich Marx
ÌbíMay 5th, 1818
Trier, Prussia
AláìsíOṣù Kẹta 14, 1883 (ọmọ ọdún 64)
London, United Kingdom
Ìgbà19th-century philosophy
AgbègbèÌmọ̀òye Apáìwọ̀òrùn
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Young Hegelian, Hegelianism, Marxism, socialism
Ìjẹlógún ganganPolitics, Economics, Philosophy, Sociology, class struggle, History,
Àròwá pàtàkìCo-founder of Marxism (with Engels), the Theory of Surplus Value, alienation and exploitation of the worker, The Communist Manifesto, Das Kapital, Materialist conception of history
Ìtọwọ́bọ̀wé

Karl Heinrich Marx (May 5, 1818 – March 14, 1883) je ara Jemani[1] amoye, aseoro-okowo oloselu, akoitan, aserojinle oloselu, aseoro-awujo, ati asekomunisti alajidide, ti awon irookan re ko ipa pataki ninu idagbasoke isekomunisti ati isesosialisti odeoni. Marx se soki ohun to unso niu ila akoko ori kinni iwe re Manifesto Komunisti, to je gbigbejade ni 1848: "Itan gbogbo awujo titi doni je itan awon ijakadi ipo." Marx jiyan pe isekapitalisti, gege bi awon sistemu awujo-oro-okowo tele, n a yio se isoro ninu re ti yio mu iparun ara re wa.[2]

Sosiolójì Lítírésò tó tèlé Èrò Karl Marx Ojú-Ìwé 36-39.

Tíórì sosiólójì tó tèlé ìlànà àti èrò Karl Marx kì I se tíórì oni, ó ti pé ti ó tí dáyé. Oludasile tíórì yìí ni Karl Marx. Orúko rè ní àwon abenugan tíórì náà fí n pe ìlànà won. Láti nnkan bí odún 1840 ni Karl Marx fúnra rè ti se èkúnréré àlàyé lórí awujo ati àsà, sùgbón ní nnkan bí Séntúrì ogún ni tíórì náà búréke láwùjo àwon akadá.


Tíórì ìsègbèfábo Ojú-Ìwé 40-52.

Tíórì ti a pè ni ìsègbèfábo lédè Yorùbá ni èdè Gèésì pè ni “Feminism”. Láti inú èdè Látìnì ni èdè Gèésì ti ya òrò náà lò èyíni “Femina”- ó túmò sí ohun gbogbo tó je mó abo tàbí àwon obìnrin. Ògíní (1996:11) so pé ònà méjì ni àlàyé lórí tíórì yìí lè pín sí.

Tíórì Asàtakò Ìmúnisìn Ojú-Ìwé 53-57.

Tíórì Asàtakò imúnisìn jé tíórì lítírésò àkókó tó kanlè wa fún lámèyító lítírésò àwon orílè èdè tó ti fojú gbooru iná ìjoba amúnisìn télè. Yorùbá bò, won ni, abini tún bini, àbèrè tun bèèrè ni kì í jé ká a pe àbúrò eni lómo eni, gbogbo àwon tíórì lítésò tí a ti tóka sí tàbí se àlàyé rè télè bí ifojuààtò-wò, ìfojú-ìhun-wò títí ó fi de tíórì Makisiisi kò kanlè wà fún lámèyító lítírésò àwon adúláwò tàbí àwon orílè èdè ti kì í se ara Yúróòpù àwon onímò kan wulè n ra tíórì náà bo lítírésò adúláwò lórùn lasan ni.

Ìsàmúlò Tíórì lítírésò Mélòó kan Ojú-Ìwé 58-104.

Síse àmúlò tíórì fún lámèyító isé onà alàwòmó lítírésò se pàtakì lóde òní. Lámèyító tí kò bá lo tíórì kan pàtó fún isé rè kò ní ìpìlè tó dúró lé. Irú isé béè kò sí ni wo àjo àwon onímò lámèyító, ko sí ibi ti a kò tí lè lo tíórì fún àlàyé tàbí ìgbélé-wón isé, ewì, eré-oníse tàbí eré-onítàn ìtàn àròso tí o fí kan eré inú fíìmù àgbéléwò tàbí alágbèéká.

Tíórì Ìfojú-àsà-ìbílè-wò Ojú-Ìwé 25-26.

Àwon agbáterù tíórì yìí so pé isé tí lítésò máa n se ni láti dáàbò bo àsà àti isese àwùjo kan, nítorí náà ohun tó gbodò je lámèyító lógún ni síse àfihàn irú àwon àsà tó súyo nínú isé onà aláwòmó lítírésò. Ojògbón Wándé Abímbólá so pé:

Therefore, in order to envolve an acceptable format for the appreciation of oral literature, we must blend our knowledge of the most up-to-date tecxxhniques of literary criticism and stylistics with a thorough understanding of Yoruba culture. Without this, any critical work is bound to be sterile.

(Kí a tó lè ri ìlànà lámèyító lítírésò ti yóò jé ìtéwógbà, a niláti jé ki irú ìlànà béè, bí o ti wù ki ó jé ti òde òní tó, ni owó àsà Yorùbá nínú, bí béè kó òfégè lásán ni isé lámèyító béè yóò jé (1982:78)

Tíórì Ìfojú-ìtàn-ìgbesi-ayé ònkòwé-wò Ojú-Ìwé 27-28.

Tíórì mìíràn tí ó tún se pàtàkì ni tíórì tí ó n sòrò nípa ìtàn ìgbésí ayé ònkòwé. Ohun tí tíórì yìí so nip é láti se àtúpalè isé onà kan, ó se pàtàkì láti mo irú eni tí ó se náà, ìtàn ìgbésí ayé rè àti àwon nkan mìíràn tó kó ipa pàtàkì kí eni náà tó dáwó lé isé náà àti ohun tí ó mú kí ó gbé isé náà gba ìlànà tí ó gbé e gbà.

Tíórì Ìfojú-ìmò-ìbára-eni-gbé-po-wo-lítírésò tàbí sosioloji lítésò Ojú-Ìwé 29-35.

Òrò tí a pè ní Sosiólójì lítírò jé òrò tí onímò èrò ìjìnlè kan ti à n pè ní Taine omo orílè èdè Faranse ro fúnra rè. Onísé lámèyító ni Taine láàárín odún 1828-1893. Ète láti so àgbéyèwò isé onà dàbí ti ìmò sáyénsì ló fa ìsèdá Sosiólójì lítírésò. Ìmò tuntun sì ló jé lágbooloé èkó nípa isé onà.

iwe ti a yewo

  • Lérè Adéyemí (2006) Tíórì Lítírésò Ní Èdè Yorùbá Sgevuituni Shebiotimo Publications, Ijebu-Ode, Nigeria; ISBN 978-2530-78-6.


Itokasi

  1. "Karl Marx". Karl Marx. Microsoft Corporation. 1993–2008. http://encarta.msn.com/encyclopedia_761555305/karl_marx.html. Retrieved 2008-12-02. "German political philosopher ...".  Marx's political philosophy developed from Western philosophical tradition, especially under the influence of Hegel; and Marx grew up in a Germanophone cultural milieu. In terms of citizenship, his birth in Trier made Marx a subject of the Kingdom of Prussia; in December 1845 he renounced his Prussian citizenship and thereafter became a stateless exile from his native Rhineland.
  2. Baird, Forrest E.; Walter Kaufmann (2008). From Plato to Derrida. Upper Saddle River, New Jersey: Pearson Prentice Hall. ISBN 0-13-158591-6.