Ositiro-Esiatiiki: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 47 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q33199 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 3: Ìlà 3:
[[Austro-Asiatic]]
[[Austro-Asiatic]]


Àwon èdè tí ó wà nínú ebí èdè yìí tó àádósàn-án. Àwon tí ó ń so wónmílíònù márùndínlógórin. Gúsù ìlà-oòrùn Asia ní pàtàkì ní China àti Indonesia ni wón ti ń so wón jù. Àwon kan sì tún ń so wón ní apá ìwò-oòrùn àríwá India àti ní Erékùsù Nicobar (Nicobar Island). Àwon èyà méta ebí èdè yìí tí ó se pàtàkì ni Mon-Khmer (tí ó jé pé nínú rè ni àwon èdè pò sí jù), Munda àti nicobarese. Àwon méjèèjì tó gbèyìn yìí ni wón ń soìwò-oòrùn àdúgbò Mon-khmer.
Àwọn èdè tí ó wà nínú ẹbí èdè yìí tó àádọ́sàn-án. Àwọn tí ó ń sọ wọ́nmílíọ̀nù márùndínlọ́gọ́rin. Gúsù ìlà-oòrùn Asia ní pàtàkì ní China àti Indonesia ni wọ́n ti ń sọ wọ́n jù. Àwọn kan sì tún ń sọ wọ́n ní apá ìwọ̀-oòrùn àríwá India àti ní Erékùsù Nicobar (Nicobar Island). Àwọn ẹ̀yà mẹ́ta ẹbí èdè yìí tí ó ṣe pàtàkì ni Mon-Khmer (tí ó jẹ́ pé nínú rẹ̀ ni àwọn èdè pọ̀ sí jù), Munda àti nicobarese. Àwọn méjèèjì tó gbẹ̀yìn yìí ni wọ́n ń sọìwọ̀-oòrùn àdúgbò Mon-khmer.
Láti fi ìmò èdá èdè pín àwon èdè yìí sòro díè nítorí pé díè nínú àwon èdè yìí ni ó ní àkosílè àti pé ìbásepò tí ó wà ní àárín àwon ebí èdè yìí àti àwon ebí èdè mìíràn kò yé èèyàn tó.
Láti fi ìmọ̀ ẹ̀dá èdè pín àwọn èdè yìí sòro díẹ̀ nítorí pé díẹ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó ní àkọsílẹ̀ àti pé ìbáṣepọ̀ tí ó wà ní àárín àwọn ẹbí èdè yìí àti àwọn ẹbí èdè mìíràn kò yé èèyàn tó.

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 13:53, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Ositiro-Esiatiiki

Austro-Asiatic

Àwọn èdè tí ó wà nínú ẹbí èdè yìí tó àádọ́sàn-án. Àwọn tí ó ń sọ wọ́n tó mílíọ̀nù márùndínlọ́gọ́rin. Gúsù ìlà-oòrùn Asia ní pàtàkì ní China àti Indonesia ni wọ́n ti ń sọ wọ́n jù. Àwọn kan sì tún ń sọ wọ́n ní apá ìwọ̀-oòrùn àríwá India àti ní Erékùsù Nicobar (Nicobar Island). Àwọn ẹ̀yà mẹ́ta ẹbí èdè yìí tí ó ṣe pàtàkì ni Mon-Khmer (tí ó jẹ́ pé nínú rẹ̀ ni àwọn èdè pọ̀ sí jù), Munda àti nicobarese. Àwọn méjèèjì tó gbẹ̀yìn yìí ni wọ́n ń sọ ní ìwọ̀-oòrùn àdúgbò Mon-khmer. Láti fi ìmọ̀ ẹ̀dá èdè pín àwọn èdè yìí sòro díẹ̀ nítorí pé díẹ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó ní àkọsílẹ̀ àti pé ìbáṣepọ̀ tí ó wà ní àárín àwọn ẹbí èdè yìí àti àwọn ẹbí èdè mìíràn kò yé èèyàn tó.