Pẹ̀lẹ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k Poarps ṣeyípòdà ojúewé PelePẹ̀lẹ́
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1: Ìlà 1:
[[Pele]]
[[Pele]]


==Pèlé ==
==Pẹ̀lẹ́ ==


Mo kí ìyáálé ilé kan pèlú òwò níjósí,
Mo kí ìyáálé ilé kan pẹ̀lú ọ̀wọ̀ níjọ́sí,


Mo ní ‘E pèlé, mà~’
Mo ní ‘Ẹ pẹ̀lẹ́, mà~’


Ó bá bínú, ó ní, ‘Mo jégbé e kó bùòdá,
Ó bá bínú, ó ní, ‘Mo jẹ́gbẹ́ kọ́ bùọ̀dá,


Tó fi ń se mí ní. “E pèlé mà.”
Tó fi ń ṣe mí ní. “Ẹ pẹ̀lẹ́ mà.”


Ó se mí ní kàyééfi mo bèbè gán-ín.
Ó ṣe mí ní kàyééfi mo bẹ̀bẹ̀ gán-ín.


Mo ní, ‘E jòwó, e má mà bínú,
Mo ní, ‘Ẹ jọ̀wọ́, má mà bínú,


Tinútinú ni mo fi kí i yín kú akitiyan.’
Tinútinú ni mo fi kí i yín kú akitiyan.’


Èyí wá mú mi rántí òrò àwon àgbà, ...
Èyí wá mú mi rántí ọ̀rọ̀ àwọn àgbà, ...


[[Irahun aja kan]]
[[Irahun aja kan]]
Ìlà 27: Ìlà 27:
==Ìráhùn Àjá Kan ==
==Ìráhùn Àjá Kan ==


Ìgbà tí mo kókó fojú bale ayé,
Ìgbà tí mo kọ́kọ́ fojú bale ayé,


Mo gbà, e è pón mi lójú kankan.
Mo gbà, ẹ̀ pọ́n mi lójú kankan.


È ń ké mi, è ń gè mí.
Ẹ̀ ń kẹ́ mi, ẹ̀ ń gẹ̀ mí.


E èsàìfúnmi lóúnje.
ẹ̀ṣàìfúnmi lóúnjẹ.


Àgàgà té e tún rámì ako nísàlè,
Àgàgà tẹ́ tún rámì akọ nísàlẹ̀,


Bí i ká jèko ìdájí ni.
Bí i ká jẹ̀kọ ìdájí ni.


Níjó eegun eran lásán,
Níjọ́ eegun ẹran lásán,


Níjó ape híha je. ...
Níjọ́ apẹ híha jẹ. ...


==Agbéraga, Lò ó Se Wò ==
==Agbéraga, Lọ̀ ọ́ Ṣe Wọ̀ ==


A ti réni tó gungi dé téńté tí ò jábó.
A ti rẹ́ni tó gungi dé téńté tí ò jábọ́.


A tí réèyàn tó mòòkùn òsè tí ò sì rì.
A tí réèyàn tó mòòkùn ọ̀sẹ̀ tí ò sì rì.


A ti rénijegba aáyán láìpòkóló.
A ti rẹ́nijẹgba aáyán láìpòkóló.


A ti réèyàn tó gbókùnrùn mì láìbì.
A ti réèyàn tó gbọ́kùnrùn mì láìbì.


A ti ródó ìrókò, a ti ródó ide.
A ti ródó ìrókò, a ti ródó idẹ.


Àyàfi ká tòkè múlé mo wálè. ...
Àyàfi ká tòkè múlé mọ wálẹ̀. ...


==Ònà Opé Pò ==
==Ọ̀nà Ọpẹ́ Pọ̀ ==


Òrò ogbón pò lénu Yorùbá.
Ọ̀rọ̀ ọgbọ́n pọ̀ lẹ́nu Yorùbá.


Omo Oòduà ló ni ká-sòrò-ìjìnlè.
Ọmọ Oòduà ló ni ká-sọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀.


Wón ti pàsamò àìmonú-ún-rò omo adáríhurun
Wọ́n ti pàṣamọ̀ àìmọnú-ún-rò ọmọ adáríhurun


Gégé bí okùnfà àìmopé-é-dú.
Gẹ́gẹ́ bí okùnfà àìmọpẹ́-ẹ́-dú.


Béèyàn ò sì wáá mo inú ún rò,
Béèyàn ò sì wáá mọ inú ún rò,


se pé torí è ni ò jé ó mopéé dú,
ṣe pé torí ẹ̀ ni ò jẹ́ ó mọpẹ́ẹ́ dú,


Sebí ó lójú ti fi ń ríran. ...
Ṣebí ó lójú ti fi ń ríran. ...


==Olúgbóyèga Àlàbá ==
==Olúgbóyèga Àlàbá ==
A bí Òjògbón Olúgbóyèga Àlàbá ní ìlú Ìgàngàn ní ìwòn àádóta odún síwájú àkókò yìí.
A bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Olúgbóyèga Àlàbá ní ìlú Ìgàngàn ní ìwọ̀n àádọ́ta ọdún síwájú àkókò yìí.
Ó lo sí ilé-èkó alákòóbèrè ti Ìjo Elétò àti ilé-èkó modá ti Ìjo yìí kan náà ní ìlú Ìgàngàn. Ó lo sí ilé-èkó Olùkóni Leo Mímó ti Ìjo Àgùdà ní ìlú Abéòkúta. Ó tún lo sí Yunifásítì ti Èkó ní Akokà....
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ìjọ Elétò àti ilé-ẹ̀kọ́ mọdá ti Ìjọ yìí kan náà ní ìlú Ìgàngàn. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni Leo Mímọ́ ti Ìjọ Àgùdà ní ìlú Abẹ́òkúta. Ó tún lọ sí Yunifásítì ti Èkó ní Akọkà....


==Jìbìtì Dògá Ìsekúse ==
==Jìbìtì Dọ̀gá Ìṣekúṣe ==


‘Eni a bá ní a ó jo
‘Ẹni a bá ní a ó jọ


Jíjù là á jù ú!’
Jíjù là á jù ú!’


Jìbìtì jo Ìsekúse
Jìbìtì jọ Ìṣekúṣe


Sé níjóìsekúse ń bò wálé ayé,
Ṣé níjọ́ìṣekúṣe ń bọ̀ wálé ayé,


Ìjo Jìbìtì kúkú ni.
Ìjọ Jìbìtì kúkú ni.


Eni ńlá ni, kì í nìkan rìn.
Ẹni ńlá ni, kì í nìkan rìn.


Nígbà Ìsekúse dáyé tán,
Nígbà Ìṣekúṣe dáyé tán,


Ó gbé e lé Jìbìtì lówó. ...
Ó gbé e lé Jìbìtì lọ́wọ́. ...




==Iwe ti a yewo==
==Iwe ti a yewo==


[[Olátúnjí Òpádòtun (2005); Àwon Akéwì Sàsàrò University Press PLC. ISBN 978-030-741-9, oju-iwe 20-35.]]
[[Ọlátúnjí Ọ̀pádọ̀tun (2005); Àwọn Akéwì Ṣàṣàrò University Press PLC. ISBN 978-030-741-9, oju-iwe 20-35.]]


[[Olatunji Opadotun]]
[[Olatunji Opadotun]]

Àtúnyẹ̀wò ní 13:53, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Pele

Pẹ̀lẹ́

Mo kí ìyáálé ilé kan pẹ̀lú ọ̀wọ̀ níjọ́sí,

Mo ní ‘Ẹ pẹ̀lẹ́, mà~’

Ó bá bínú, ó ní, ‘Mo jẹ́gbẹ́ ẹ kọ́ bùọ̀dá,

Tó fi ń ṣe mí ní. “Ẹ pẹ̀lẹ́ mà.”

Ó ṣe mí ní kàyééfi mo bẹ̀bẹ̀ gán-ín.

Mo ní, ‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ má mà bínú,

Tinútinú ni mo fi kí i yín kú akitiyan.’

Èyí wá mú mi rántí ọ̀rọ̀ àwọn àgbà, ...

Irahun aja kan

Aja

Irahun

Ìráhùn Àjá Kan

Ìgbà tí mo kọ́kọ́ fojú bale ayé,

Mo gbà, ẹ ẹ̀ pọ́n mi lójú kankan.

Ẹ̀ ń kẹ́ mi, ẹ̀ ń gẹ̀ mí.

Ẹ ẹ̀ sì ṣàìfúnmi lóúnjẹ.

Àgàgà tẹ́ ẹ tún rámì akọ nísàlẹ̀,

Bí i ká jẹ̀kọ ìdájí ni.

Níjọ́ eegun ẹran lásán,

Níjọ́ apẹ híha jẹ. ...

Agbéraga, Lọ̀ ọ́ Ṣe Wọ̀

A ti rẹ́ni tó gungi dé téńté tí ò jábọ́.

A tí réèyàn tó mòòkùn ọ̀sẹ̀ tí ò sì rì.

A ti rẹ́ni tó jẹgba aáyán láìpòkóló.

A ti réèyàn tó gbọ́kùnrùn mì láìbì.

A ti ródó ìrókò, a ti ródó idẹ.

Àyàfi ká tòkè múlé mọ wálẹ̀. ...

Ọ̀nà Ọpẹ́ Pọ̀

Ọ̀rọ̀ ọgbọ́n pọ̀ lẹ́nu Yorùbá.

Ọmọ Oòduà ló ni ká-sọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀.

Wọ́n ti pàṣamọ̀ àìmọnú-ún-rò ọmọ adáríhurun

Gẹ́gẹ́ bí okùnfà àìmọpẹ́-ẹ́-dú.

Béèyàn ò sì wáá mọ inú ún rò,

Tó ṣe pé torí ẹ̀ ni ò jẹ́ ó mọpẹ́ẹ́ dú,

Ṣebí ó lójú ti fi ń ríran. ...

Olúgbóyèga Àlàbá

A bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Olúgbóyèga Àlàbá ní ìlú Ìgàngàn ní ìwọ̀n àádọ́ta ọdún síwájú àkókò yìí.

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ìjọ Elétò àti ilé-ẹ̀kọ́ mọdá ti Ìjọ yìí kan náà ní ìlú Ìgàngàn. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni Leo Mímọ́ ti Ìjọ Àgùdà ní ìlú Abẹ́òkúta. Ó tún lọ sí Yunifásítì ti Èkó ní Akọkà....

Jìbìtì Dọ̀gá Ìṣekúṣe

‘Ẹni a bá ní a ó jọ

Jíjù là á jù ú!’

Jìbìtì jọ Ìṣekúṣe

Ṣé níjọ́ tí ìṣekúṣe ń bọ̀ wálé ayé,

Ìjọ Jìbìtì kúkú ni.

Ẹni ńlá ni, kì í nìkan rìn.

Nígbà Ìṣekúṣe dáyé tán,

Ó gbé e lé Jìbìtì lọ́wọ́. ...


Iwe ti a yewo

Ọlátúnjí Ọ̀pádọ̀tun (2005); Àwọn Akéwì Ṣàṣàrò University Press PLC. ISBN 978-030-741-9, oju-iwe 20-35.

Olatunji Opadotun

link title