Sẹ̀mítíìkì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 77 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q34049 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 3: Ìlà 3:
[[Semitiiki]]
[[Semitiiki]]


Semitic ni àwon ènìyàn ka ju ti o si ye wonsíbè àwon èdè kan wa ti wonmo rárá nipá sise arópò extant ati extinet kan. Semitic se ipate adoofa lorisiirisi. Nípa ìsàkóso ti ìbílè won sùgbón dosini kan àbò lo wà lábé ìsàkóso àwon Arabiki, sùgbón àwon kan rò wípé ko ba ojú mu lati se be.
Semitic ni àwọn ènìyàn ka ju ti o ṣi ye wọnsíbẹ̀ àwọn èdè kan wa ti wọnmọ rárá nipá ṣiṣe arópò extant ati extinet kan. Semitic ṣe ipatẹ adọọfa lorisiirisi. Nípa ìṣàkóṣo ti ìbílẹ̀ wọn ṣùgbọ́n dọsini kan àbọ̀ lo wà lábẹ́ ìṣàkóṣo àwọn Arabiki, ṣùgbọ́n àwọn kan rò wípé ko ba ojú mu lati ṣe bẹ.
Àwon Oludari kan gba pe Semitic a le ri oruko won ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwo Òòrun àti Gusu lábé ipin eka ìdílé kan sùgbón aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pèlú èka ìdílé Gúsù. Arákùnrin tí Orúko rè ń je Hetzron (1972: 15-16)5 se àríyànjiyàn lórí ipò
Àwọn Oludari kan gba pe Semitic a le ri orukọ wọn ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwọ Òòrun àti Guṣu lábẹ́ ipin ẹka ìdílé kan ṣùgbọ́n aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pẹ̀lú ẹ̀ka ìdílé Gúṣù. Arákùnrin tí Orúkọ rẹ̀ ń jẹ Hetzron (1972: 15-16)5 ṣe àríyànjiyàn lórí ipò


(1) Eka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jé ayé òlàjú tó ti kojá lo ti àwon Assyrians àti Babylonians nígbà to si je pé Akkadian wà ní lílò fún nnkan bi Odún meji milinionu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwò Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúsù àríwá si èka. Ti àwon Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àsìkò ìgbà ayé àtijó ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wón ń so lati nnkan bí Centiuri mewa BC. Séyìn. nnkan bì Centiuri méfà séyìn àwon kirisiteni Aramaic nìkan ní ó jé èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilè jeàwon èdè tí á ń so ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwò Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwon Olùso èdè ní Assyrian (200).
(1) Ẹka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jẹ́ ayé òlàjú tó ti kọjá lọ ti àwọn Assyrians àti Babylonians nígbà to ṣi jẹ pé Akkadian wà ní lílò fún nǹkan bi Ọdún meji miliniọnu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwọ̀ Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúṣù àríwá ṣi ẹ̀ka. Ti àwọn Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àṣìkò ìgbà ayé àtijọ́ ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wọ́n ń ṣọ lati nǹkan bí Centiuri mẹwa BC. Ṣẹ́yìn. nǹkan bì Centiuri mẹ́fà sẹ́yìn àwọn kirisitẹni Aramaic nìkan ní ó jẹ́ èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilẹ̀ jẹàwọn èdè tí á ń ṣọ ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwọ̀ Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwọn Olùṣo èdè ní Assyrian (200).


2. Eka arìngbùngbùn Gusu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí paré legbe èdè ìlà Òòrun gégé bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew.
2. Ẹka arìngbùngbùn Guṣu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí parẹ́ legbẹ èdè ìlà Òòrun gẹ́gẹ́ bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew.
Àwon phonecian, ni tòótó won ń sòrò nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwon keteji (Carthage) níbi tí á tí mo hàn-án bí puniki.
Àwọn phonecian, ni tòótó wọn ń sọ̀rọ̀ nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwọn keteji (Carthage) níbi tí á tí mọ hàn-án bí puniki.
Èdè ìgbàlódé ti àwon Hébérù ń so ni Isrealis lo se àtúnse re (4, 510). Èdè tí àwon Ras Shamra àti Uguritic ń so kàyéfì lo jé. Èdè to ti péàwon Quran ń lò láti Centiuri kerin AD, lo wà sùgbón nígbà tó yá wón padà sí tí Centiuri karun BC; sùgbón síbè wón ko so mó.
Èdè ìgbàlódé ti àwọn Hébérù ń ṣọ ni Isrealis lo ṣe àtúnṣe rẹ (4, 510). Èdè tí àwọn Ras Shamra àti Uguritic ń sọ kàyéfì lo jẹ́. Èdè to ti pẹ́àwọn Quran ń lò láti Centiuri kẹrin AD, lo wà ṣùgbọ́n nígbà tó yá wọ́n padà ṣí tí Centiuri karun BC; ṣùgbọ́n síbẹ̀ wọ́n ko ṣọ mọ́.
Loni Orísìírìsí ìpínlè Arábìkì tí wón ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwò Afíríkà. Ní Áfíríkà àwon èdè tó hàn gbegedé won si pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti won ń so ní Mauritania àti díè lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), won ń so díè ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wón ń so ní Àríwá Sudan sùgbón pèlú àwon Olùso èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wón ń so Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) sùgbón wón ń so èdè yìí díè ní Libya àti Egypt.
Loni Orísìírìsí ìpínlẹ̀ Arábìkì tí wọ́n ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwọ̀ Afíríkà. Ní Áfíríkà àwọn èdè tó hàn gbegedé wọn ṣi pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti wọn ń ṣọ ní Mauritania àti díẹ̀ lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), wọn ń ṣọ díẹ̀ ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wọ́n ń sọ ní Àríwá Sudan ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn Olùṣọ èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wọ́n ń sọ Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) ṣùgbọ́n wọ́n ń ṣọ èdè yìí díẹ̀ ní Libya àti Egypt.
Ó dá hàn yàtò sí èdá òrò aláwomo èdè oni ti Arabiki sùgbón èdè Arabiki ní a ń lò fún èkó Ìsàkóso àti Ìgbòòrò Ìbánisòrò bakan náà a ń lo gégé bi èdè kejì ó si jé èdè ìpìnlè àkóko fún èdè Arábìkì.
Ó dá hàn yàtọ̀ ṣí ẹ̀dá ọ̀rọ̀ aláwomọ èdè oni ti Arabiki ṣùgbọ́n èdè Arabiki ní a ń lò fún ẹ̀kọ́ Ìṣàkóṣo àti Ìgbòòrò Ìbánisòrọ̀ bakan náà a ń lo gẹ́gẹ́ bi èdè kejì ó si jẹ́ èdè ìpìnlẹ̀ àkọ́kọ fún èdè Arábìkì.
Ìyàtò èdá Ìgbédègbéyò wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkókó Ferguson (1959) Maltese (330) won ń sòrò nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlè èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki sùgbón tí ó tí tàn ka láàrín àwon Italiàni.
Ìyàtọ̀ ẹ̀dá Ìgbẹ́dègbẹ́yọ̀ wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkọ́kọ́ Ferguson (1959) Maltese (330) wọn ń sọ̀rọ̀ nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlẹ̀ èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki ṣùgbọ́n tí ó tí tàn ka láàrín àwọn Italiàni.




(3) Sémítìkì to wa ní Gusu kún fún àwon Arabiki Gusu àti Ethic Semitic Sùgbón àwon ti télè kún fún Orísìírísí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mò láti ìwò Òòrùn Gusu Arábìkì àkosílè rè tí wà láti Centiuri méjo BC pèlú Arábìkì ti Gusu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Sùgbón ki i se gbogbo àwon Òmòwé to gboye nínú koko ise kan lo fara mò.
(3) Sémítìkì to wa ní Guṣu kún fún àwọn Arabiki Guṣu àti Ethic Semitic Ṣùgbọ́n àwọn ti tẹ́lẹ̀ kún fún Orísìíríṣí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mọ̀ láti ìwọ̀ Òòrùn Guṣu Arábìkì àkọsílè rè tí wà láti Centiuri méjọ BC pẹ̀lú Arábìkì ti Guṣu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Ṣùgbọ́n ki i se gbogbo àwọn Òmòwé to gboye nínú koko isẹ kan lo fara mọ̀.
Ethic-Semitic kún fún àwon ará Àríwá Eghiopic àti èka òrò aláwòmó àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní èka Gusu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín.
Ethic-Semitic kún fún àwọn ará Àríwá Eghiopic àti ẹ̀ka ọ̀rọ̀ aláwòmọ́ àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní ẹ̀ka Guṣu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín.
Amharic (20, 000) èdè Ethopia je tí gbogbo gbo ó wà lára ti télè gégé bi Harari (26), O jé eni ti ahón rè fanimóra tí ó si jeìbìlè si gbogbo ìlú Harari gbogbo àwon egbé atòdefimò gbárajo pèlú àwon ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gégé bí Soddo (104) yàtò si tí àringbùngbùn tí ìwò Òòrùn pèlú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wón je sòròsòrò (1,856) Orísìírírìsí nnkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a si se àpínsowoó rè si egbé èyí ti o wa láàrín. Ó se pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á si fi hàn gégé bi èdè kan.
Amharic (20, 000) èdè Ethopia jẹ tí gbogbo gbo ó wà lára ti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Harari (26), O jé ẹni ti ahọ́n rẹ̀ fanimọ́ra tí ó si jẹìbìlẹ̀ ṣi gbogbo ìlú Harari gbogbo àwọn ẹgbẹ́ atòdefimọ̀ gbárajọ pẹ̀lú àwọn ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gẹ́gẹ́ bí Soddo (104) yàtọ̀ si tí àringbùngbùn tí ìwọ̀ Òòrùn pẹ̀lú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wọ́n jẹ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ (1,856) Orísìírírìsí nǹkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a ṣi ṣe àpínsowoó rẹ̀ ṣi ẹgbé èyí ti o wa láàrín. Ó ṣe pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á ṣi fi hàn gẹ́gẹ́ bi èdè kan.


[[Ẹ̀ka:Àwọn èdè]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn èdè]]

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 13:55, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Semitic

Semitiiki

Semitic ni àwọn ènìyàn ka ju ti o ṣi ye wọn jù síbẹ̀ àwọn èdè kan wa ti wọn kò mọ rárá nipá ṣiṣe arópò extant ati extinet kan. Semitic ṣe ipatẹ adọọfa lorisiirisi. Nípa ìṣàkóṣo ti ìbílẹ̀ wọn ṣùgbọ́n dọsini kan àbọ̀ lo wà lábẹ́ ìṣàkóṣo àwọn Arabiki, ṣùgbọ́n àwọn kan rò wípé ko ba ojú mu lati ṣe bẹ. Àwọn Oludari kan gba pe Semitic a le ri orukọ wọn ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwọ Òòrun àti Guṣu lábẹ́ ipin ẹka ìdílé kan ṣùgbọ́n aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pẹ̀lú ẹ̀ka ìdílé Gúṣù. Arákùnrin tí Orúkọ rẹ̀ ń jẹ Hetzron (1972: 15-16)5 ṣe àríyànjiyàn lórí ipò

(1) Ẹka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jẹ́ ayé òlàjú tó ti kọjá lọ ti àwọn Assyrians àti Babylonians nígbà to ṣi jẹ pé Akkadian wà ní lílò fún nǹkan bi Ọdún meji miliniọnu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwọ̀ Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúṣù àríwá ṣi ẹ̀ka. Ti àwọn Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àṣìkò ìgbà ayé àtijọ́ ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wọ́n ń ṣọ lati nǹkan bí Centiuri mẹwa BC. Ṣẹ́yìn. nǹkan bì Centiuri mẹ́fà sẹ́yìn àwọn kirisitẹni Aramaic nìkan ní ó jẹ́ èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilẹ̀ jẹ pé àwọn èdè tí á ń ṣọ ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwọ̀ Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwọn Olùṣo èdè ní Assyrian (200).


2. Ẹka arìngbùngbùn Guṣu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí parẹ́ legbẹ èdè ìlà Òòrun gẹ́gẹ́ bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew. Àwọn phonecian, ni tòótó wọn ń sọ̀rọ̀ nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwọn keteji (Carthage) níbi tí á tí mọ hàn-án bí puniki. Èdè ìgbàlódé ti àwọn Hébérù ń ṣọ ni Isrealis lo ṣe àtúnṣe rẹ (4, 510). Èdè tí àwọn Ras Shamra àti Uguritic ń sọ kàyéfì lo jẹ́. Èdè to ti pẹ́ tí àwọn Quran ń lò láti Centiuri kẹrin AD, lo wà ṣùgbọ́n nígbà tó yá wọ́n padà ṣí tí Centiuri karun BC; ṣùgbọ́n síbẹ̀ wọ́n ko ṣọ mọ́. Loni Orísìírìsí ìpínlẹ̀ Arábìkì tí wọ́n ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwọ̀ Afíríkà. Ní Áfíríkà àwọn èdè tó hàn gbegedé wọn ṣi pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti wọn ń ṣọ ní Mauritania àti díẹ̀ lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), wọn ń ṣọ díẹ̀ ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wọ́n ń sọ ní Àríwá Sudan ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn Olùṣọ èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wọ́n ń sọ Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) ṣùgbọ́n wọ́n ń ṣọ èdè yìí díẹ̀ ní Libya àti Egypt. Ó dá hàn yàtọ̀ ṣí ẹ̀dá ọ̀rọ̀ aláwomọ èdè oni ti Arabiki ṣùgbọ́n èdè Arabiki ní a ń lò fún ẹ̀kọ́ Ìṣàkóṣo àti Ìgbòòrò Ìbánisòrọ̀ bakan náà a ń lo gẹ́gẹ́ bi èdè kejì ó si jẹ́ èdè ìpìnlẹ̀ àkọ́kọ fún èdè Arábìkì. Ìyàtọ̀ ẹ̀dá Ìgbẹ́dègbẹ́yọ̀ wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkọ́kọ́ Ferguson (1959) Maltese (330) wọn ń sọ̀rọ̀ nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlẹ̀ èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki ṣùgbọ́n tí ó tí tàn ka láàrín àwọn Italiàni.


(3) Sémítìkì to wa ní Guṣu kún fún àwọn Arabiki Guṣu àti Ethic Semitic Ṣùgbọ́n àwọn ti tẹ́lẹ̀ kún fún Orísìíríṣí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mọ̀ láti ìwọ̀ Òòrùn Guṣu Arábìkì àkọsílè rè tí wà láti Centiuri méjọ BC pẹ̀lú Arábìkì ti Guṣu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Ṣùgbọ́n ki i se gbogbo àwọn Òmòwé to gboye nínú koko isẹ kan lo fara mọ̀. Ethic-Semitic kún fún àwọn ará Àríwá Eghiopic àti ẹ̀ka ọ̀rọ̀ aláwòmọ́ àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní ẹ̀ka Guṣu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín. Amharic (20, 000) èdè Ethopia jẹ tí gbogbo gbo ó wà lára ti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Harari (26), O jé ẹni ti ahọ́n rẹ̀ fanimọ́ra tí ó si jẹ tí ìbìlẹ̀ ṣi gbogbo ìlú Harari gbogbo àwọn ẹgbẹ́ atòdefimọ̀ gbárajọ pẹ̀lú àwọn ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gẹ́gẹ́ bí Soddo (104) yàtọ̀ si tí àringbùngbùn tí ìwọ̀ Òòrùn pẹ̀lú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wọ́n jẹ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ (1,856) Orísìírírìsí nǹkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a ṣi ṣe àpínsowoó rẹ̀ ṣi ẹgbé èyí ti o wa láàrín. Ó ṣe pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á ṣi fi hàn gẹ́gẹ́ bi èdè kan.