Táyọ̀ Awótúsìn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k Poarps ṣeyípòdà ojúewé Tayo AwotusinTáyọ̀ Awótúsìn
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1: Ìlà 1:
==Tayo Awotusin==
==Tayo Awotusin==


[[Táyò Awótúsìn àti Chris Odiiibe]]: Níbi ogun tí ó n selè ní Leberia, wón pa Táyò Awótúsìn ti ilé-isé ìwé-ìròyìn Champion àti Chris Odiiibe ti ilé-isé ìwé-ìròyìn Guardian ní odún 1991 níbi tí wón ti n se isé òòjó won.
[[Táyọ̀ Awótúsìn àti Chris Odiiibe]]: Níbi ogun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní Leberia, wọ́n pa Táyọ̀ Awótúsìn ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn Champion àti Chris Odiiibe ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn Guardian ní ọdún 1991 níbi tí wọ́n ti ń ṣe iṣẹ́ òòjọ́ wọn.


==Proscription of Newspaper==
==Proscription of Newspaper==


[[Proscription of Newspaper]]: Ní osù kéje odún 1993, ìjoba àpapò gbésètítè jáde ìwé-ìròyìn àwon The Concord Press, the Punch Press, the Sketch Press, the Observer Press and Abuja Newsday Press. Wónwongbódò te ìwé-ìròyìn jade fún odún kan. Ní osù kéfà odún 1994, ìjoba àpapò tún so pé kí the Concord Press, The Punch Press àti the Guardian Press má té ìwé-ìròyìn won jade jún odún mìíràn.
[[Proscription of Newspaper]]: Ní oṣù kéje ọdún 1993, ìjọba àpapọ̀ gbẹ́sẹ̀títẹ̀ jáde ìwé-ìròyìn àwọn The Concord Press, the Punch Press, the Sketch Press, the Observer Press and Abuja Newsday Press. Wọ́nwọngbọ́dọ̀ tẹ ìwé-ìròyìn jade fún ọdún kan. Ní oṣù kẹ́fà ọdún 1994, ìjọba àpapọ̀ tún sọ pé kí the Concord Press, The Punch Press àti the Guardian Press má tẹ́ ìwé-ìròyìn wọn jade jún ọdún mìíràn.


==Thirty Minutes of Corruption in Nigeria==
==Thirty Minutes of Corruption in Nigeria==


[[Thirty Minutes of Corruption in Nigeria]]: Ní odún 1994, ilé-isé telífísàn kan ní ilè Àméríkàorúko rè n jé the American Colombia Broadcasting Service (CBS), ní osù kéjìlá odún gbé ètò kan jáde lórí ìwá ìbajé tí ó pè ní ‘thirty minutes of corruption in Nigeria. Léyìn ètò yìí, ìjobá àpapó ní kí gbogbo àwon eniòrò ìbàjé náà kan kí won sì pè wón léjó.
[[Thirty Minutes of Corruption in Nigeria]]: Ní ọdún 1994, ilẹ́-iṣẹ́ tẹlífísàn kan ní ilẹ̀ Àmẹ́ríkàorúkọ rẹ̀ ń jẹ́ the American Colombia Broadcasting Service (CBS), ní oṣù kéjìlá ọdún gbé ètò kan jáde lórí ìwá ìbajẹ́ tí ó pè ní ‘thirty minutes of corruption in Nigeria. Lẹ́yìn ètò yìí, ìjọbá àpapọ́ ní kí gbogbo àwọn ẹniọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ náà kan kí wọn sì pè wọ́n lẹ́jọ́.


==Iwe iroyin gbowo lori==
==Iwe iroyin gbowo lori==


[[Owó ìwé ìròyìn]]: Ní ojó kìíní osù kéjìlá odún 1963, owó ìwé ìròyìn kúrò ní kóbò mérin ó di kóbò márùn-ún.
[[Owó ìwé ìròyìn]]: Ní ọjọ́ kìíní oṣù kéjìlá ọdún 1963, owó ìwé ìròyìn kúrò ní kọ́bọ̀ mẹ́rin ó di kọ́bọ̀ márùn-ún.

Àtúnyẹ̀wò ní 13:56, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Tayo Awotusin

Táyọ̀ Awótúsìn àti Chris Odiiibe: Níbi ogun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní Leberia, wọ́n pa Táyọ̀ Awótúsìn ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn Champion àti Chris Odiiibe ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn Guardian ní ọdún 1991 níbi tí wọ́n ti ń ṣe iṣẹ́ òòjọ́ wọn.

Proscription of Newspaper

Proscription of Newspaper: Ní oṣù kéje ọdún 1993, ìjọba àpapọ̀ gbẹ́sẹ̀ lé títẹ̀ jáde ìwé-ìròyìn àwọn The Concord Press, the Punch Press, the Sketch Press, the Observer Press and Abuja Newsday Press. Wọ́n ní wọn kò gbọ́dọ̀ tẹ ìwé-ìròyìn jade fún ọdún kan. Ní oṣù kẹ́fà ọdún 1994, ìjọba àpapọ̀ tún sọ pé kí the Concord Press, The Punch Press àti the Guardian Press má tẹ́ ìwé-ìròyìn wọn jade jún ọdún mìíràn.

Thirty Minutes of Corruption in Nigeria

Thirty Minutes of Corruption in Nigeria: Ní ọdún 1994, ilẹ́-iṣẹ́ tẹlífísàn kan ní ilẹ̀ Àmẹ́ríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ the American Colombia Broadcasting Service (CBS), ní oṣù kéjìlá ọdún gbé ètò kan jáde lórí ìwá ìbajẹ́ tí ó pè ní ‘thirty minutes of corruption in Nigeria. Lẹ́yìn ètò yìí, ìjọbá àpapọ́ ní kí gbogbo àwọn ẹni tí ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ náà kan kí wọn sì pè wọ́n lẹ́jọ́.

Iwe iroyin gbowo lori

Owó ìwé ìròyìn: Ní ọjọ́ kìíní oṣù kéjìlá ọdún 1963, owó ìwé ìròyìn kúrò ní kọ́bọ̀ mẹ́rin ó di kọ́bọ̀ márùn-ún.