Thomas Hardy: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q132805 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents

Ìlà 14: Ìlà 14:
| spouse = Emma Lavinia Gifford
(1874–1912)
[[Florence Dugdale]]
(1914–1928)
| spouse = Emma Lavinia Gifford
(1874–1912)
[[Florence Dugdale]]
(1914–1928)

A bí '''Thomas Hardy''' (2 June 1840 – 11 January 1928) ní 1840. Ó kú ní 1928. Ó máa n ko ìtàn-àròso àti ewì. Omo ìlú Dorset ni. Kòlà-kò-sagbe sì ni pèlú. Ó ti di ‘architect’ kí ó tó di 1873. Ó fi isé yìí sílè láti máa ko ìwé. Ó gbà pé akéwì ni òun. Ó koegbérún ewì irú èyí tí a máa n pè ní ‘short lyrics’. Ewì rè máa n kún fún òótó ó sì máa n mú ènìyàn lára.
A bí '''Thomas Hardy''' (2 June 1840 – 11 January 1928) ní 1840. Ó kú ní 1928. Ó máa ń kọ ìtàn-àròsọ àti ewì. Ọmọ ìlú Dorset ni. Kòlà-kò-ṣagbe sì ni pẹ̀lú. Ó ti di ‘architect’ kí ó tó di 1873. Ó fi iṣẹ́ yìí sílẹ̀ láti máa kọ ìwé. Ó gbà pé akéwì ni òun. Ó kọẹgbẹ́rún ewì irú èyí tí a máa ń pè ní ‘short lyrics’. Ewì rẹ̀ máa ń kún fún òótọ́ ó sì máa ń mú ènìyàn lára.

{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 13:57, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Thomas Hardy
Iṣẹ́Novelist, Poet, and Short Story writer
Literary movementNaturalism
SpouseEmma Lavinia Gifford
(1874–1912)
Florence Dugdale
(1914–1928)

A bí Thomas Hardy (2 June 1840 – 11 January 1928) ní 1840. Ó kú ní 1928. Ó máa ń kọ ìtàn-àròsọ àti ewì. Ọmọ ìlú Dorset ni. Kòlà-kò-ṣagbe sì ni pẹ̀lú. Ó ti di ‘architect’ kí ó tó di 1873. Ó fi iṣẹ́ yìí sílẹ̀ láti máa kọ ìwé. Ó gbà pé akéwì ni òun. Ó kọ tó ẹgbẹ́rún ewì irú èyí tí a máa ń pè ní ‘short lyrics’. Ewì rẹ̀ máa ń kún fún òótọ́ ó sì máa ń mú ènìyàn lára.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]