Jacob Zuma: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
update
k update
Ìlà 4: Ìlà 4:
|image = Jacob G. Zuma - World Economic Forum Annual Meeting Davos 2010.jpg
|image = Jacob G. Zuma - World Economic Forum Annual Meeting Davos 2010.jpg
|office = [[President of South Africa]]
|office = [[President of South Africa]]
|deputy = [[Kgalema Motlanthe]]
|deputy = [[Kgalema Motlanthe]]<br />[[Cyril Ramaphosa]]
|term_start = 9 May 2009
|term_start = 9 May 2009
|term_end = 14 February 2018
|term_end = 14 February 2018
Ìlà 10: Ìlà 10:
|successor = [[Cyril Ramaphosa]]
|successor = [[Cyril Ramaphosa]]
|office2 = [[African National Congress|President of the African National Congress]]
|office2 = [[African National Congress|President of the African National Congress]]
|deputy2 = [[Kgalema Motlanthe]]
|deputy2 = [[Kgalema Motlanthe]]<br />[[Cyril Ramaphosa]]
|term_start2 = 18 December 2007
|term_start2 = 18 December 2007
|term_end2 = 18 December 2017
|term_end2 = 18 December 2017

Àtúnyẹ̀wò ní 08:45, 16 Oṣù Kejì 2018


Jacob Zuma
President of South Africa
In office
9 May 2009 – 14 February 2018
DeputyKgalema Motlanthe
Cyril Ramaphosa
AsíwájúKgalema Motlanthe
Arọ́pòCyril Ramaphosa
President of the African National Congress
In office
18 December 2007 – 18 December 2017
DeputyKgalema Motlanthe
Cyril Ramaphosa
AsíwájúThabo Mbeki
Arọ́pòCyril Ramaphosa
Member of Parliament
In office
1999–2005
Deputy President of South Africa
In office
14 June 1999 – 14 June 2005
ÀàrẹThabo Mbeki
AsíwájúThabo Mbeki
Arọ́pòPhumzile Mlambo-Ngcuka
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Jacob Gedleyihlekisa Zuma

12 Oṣù Kẹrin 1942 (1942-04-12) (ọmọ ọdún 82)
Inkandla, South Africa
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAfrican National Congress (1959–present)
Other political
affiliations
Communist Party (1963–present)
(Àwọn) olólùfẹ́Gertrude Sizakele Khumalo (1973–present)
Kate Zuma (1976–2000)[1]
Nkosazana Dlamini (1982–1998)
Nompumelelo Ntuli (2008 – present)
Àwọn ọmọ20

Jacob Zuma jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà tẹ́lẹ́.[2][3][4] Ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé African National Congress (ANC) ní Guusu Afrika.[5] Olóyè ni ó jé ní àárín àwọn Zulu. Ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bí ọmọ méjì fún un. 1943 ni wọ́n bí Jacob Zuma. Ìyàwó rẹ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ ní jẹ́ Kate pa ara rẹ̀ ní ọdúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwọn ti ṣe fún ọfún mẹ́rìnlélógún kò rọgbọ. Ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní ọdún 2005 ni President thabo Mbaki yọ Zuma kúrò ní ipò igbákejì àrẹ nítorí ìwà ìbàjẹ́.[6] Ní ọdún 2006 ni wón fi ẹ̀sùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà.

àwọn ìtọ́kasí