Kaycee Madu: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ẹ̀ka; DEFAULTSORT; intro paragraph wikilink with EN:YO
Ìlà 29: Ìlà 29:
| alma_mater=
| alma_mater=
}}
}}
'''Kaycee (Kelechi) Madu''' jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà <ref name="TheCable 2020">{{cite web | title=CLOSE-UP: Madu, Nigerian-born lawyer, appointed justice minister in Canadian province | website=TheCable | date=2020-08-26 | url=https://www.thecable.ng/close-up-madu-nigerian-born-lawyer-appointed-justice-minister-in-canadian-province | access-date=2020-08-27}}</ref><ref name="The Sun Nigeria 2020">{{cite web | title=Obi hails Kaycee Madu on new appointment | website=The Sun Nigeria | date=2020-08-27 | url=https://www.sunnewsonline.com/obi-hails-kaycee-madu-on-new-appointment/ | access-date=2020-08-27}}</ref> ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè Canada. Òun ni Mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn Ìpínlẹ̀ Alberta ní orílẹ̀-èdè Canada. Wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Alberta lọ́dún 2019, láti ṣojú ẹkùn ìdìbò [[electoral district]].<ref>{{cite web|author=Derek Van Diest Updated: April 16, 2019 |url=https://edmontonjournal.com/news/politics/results-kacyee-madu-wins-edmonton-south-west-in-tightly-contested-battleground |title=Results: Kacyee Madu wins Edmonton-South West in tightly contested battleground |publisher=Edmonton Journal |date= |accessdate=2019-04-17}}</ref> Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2019,Wọ́n Madu sínú Ìgbìmọ̀ ìṣèjọba, [[Executive Council of Alberta]] gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò olú-ìlú náà. Ìpò yìí ló dìmú títí dọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí wọ́n tún fi yàn án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà ètò ìdájọ́ àti Amọ̀fin-àgbà ní Alberta lórílẹ̀-èdè Canada.
'''Kaycee (Kelechi) Madu''' jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà <ref name="TheCable 2020">{{cite web | title=CLOSE-UP: Madu, Nigerian-born lawyer, appointed justice minister in Canadian province | website=TheCable | date=2020-08-26 | url=https://www.thecable.ng/close-up-madu-nigerian-born-lawyer-appointed-justice-minister-in-canadian-province | access-date=2020-08-27}}</ref><ref name="The Sun Nigeria 2020">{{cite web | title=Obi hails Kaycee Madu on new appointment | website=The Sun Nigeria | date=2020-08-27 | url=https://www.sunnewsonline.com/obi-hails-kaycee-madu-on-new-appointment/ | access-date=2020-08-27}}</ref> ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè [[Kánádà]]. Òun ni Mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn Ìpínlẹ̀ Alberta ní orílẹ̀-èdè Kánádà. Wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Alberta lọ́dún 2019, láti ṣojú ẹkùn ìdìbò [[electoral district]].<ref>{{cite web|author=Derek Van Diest Updated: April 16, 2019 |url=https://edmontonjournal.com/news/politics/results-kacyee-madu-wins-edmonton-south-west-in-tightly-contested-battleground |title=Results: Kacyee Madu wins Edmonton-South West in tightly contested battleground |publisher=Edmonton Journal |date= |accessdate=2019-04-17}}</ref> Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2019,Wọ́n Madu sínú Ìgbìmọ̀ ìṣèjọba, [[Executive Council of Alberta]] gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò olú-ìlú náà. Ìpò yìí ló dìmú títí dọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí wọ́n tún fi yàn án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà ètò ìdájọ́ àti Amọ̀fin-àgbà ní Alberta lórílẹ̀-èdè Kánádà.


Pẹ̀lú àṣẹ láti òfin ìgbìmọ̀ iìṣèjọba, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Alberta fún Madu ni oyè Queen's Counsel lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2020. Oyè Queen's Counsel ni oyè tí ó ga jùlọ tí wọ́n máa ń fún àwọn aṣòfin tó bá dáńgájíá nípa ìdàgbàsókè òfin àti ìlú
Pẹ̀lú àṣẹ láti òfin ìgbìmọ̀ iìṣèjọba, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Alberta fún Madu ni oyè Queen's Counsel lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2020. Oyè Queen's Counsel ni oyè tí ó ga jùlọ tí wọ́n máa ń fún àwọn aṣòfin tó bá dáńgájíá nípa ìdàgbàsókè òfin àti ìlú
Ìlà 54: Ìlà 54:
==Àwọn Ìtọ́kasí==
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
{{Reflist}}

{{DEFAULTSORT:Madu, Kaycee}}
[[Ẹ̀ka:Àwọn ará Kánádà]]

Àtúnyẹ̀wò ní 15:36, 27 Oṣù Kẹjọ 2020


Kaycee Madu

Minister of Justice and Solicitor General of Alberta
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
August 25, 2020
PremierJason Kenney
AsíwájúDoug Schweitzer
Minister of Municipal Affairs of Alberta
In office
April 30, 2019 – August 25, 2020
PremierJason Kenney
AsíwájúShaye Anderson
Arọ́pòTracy Allard
Member of the Legislative Assembly of Alberta for Edmonton-South West
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
April 16, 2019
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÀdàkọ:Birth based on age as of date[1]
Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Conservative Party
ResidenceEdmonton, Alberta
Occupationlawyer

Kaycee (Kelechi) Madu jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà [2][3] ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè Kánádà. Òun ni Mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn Ìpínlẹ̀ Alberta ní orílẹ̀-èdè Kánádà. Wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Alberta lọ́dún 2019, láti ṣojú ẹkùn ìdìbò electoral district.[4] Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2019,Wọ́n Madu sínú Ìgbìmọ̀ ìṣèjọba, Executive Council of Alberta gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò olú-ìlú náà. Ìpò yìí ló dìmú títí dọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí wọ́n tún fi yàn án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà ètò ìdájọ́ àti Amọ̀fin-àgbà ní Alberta lórílẹ̀-èdè Kánádà.

Pẹ̀lú àṣẹ láti òfin ìgbìmọ̀ iìṣèjọba, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Alberta fún Madu ni oyè Queen's Counsel lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2020. Oyè Queen's Counsel ni oyè tí ó ga jùlọ tí wọ́n máa ń fún àwọn aṣòfin tó bá dáńgájíá nípa ìdàgbàsókè òfin àti ìlú


Àdàkọ:Canadian cabinet member navigational box headerÀdàkọ:Ministry box cabinet postsÀdàkọ:S-end

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. Paige Parsons (2019-04-10). "Alberta Election 2019 riding profile: Edmonton-South West". Edmonton Journal. Retrieved 2019-04-17. 
  2. "CLOSE-UP: Madu, Nigerian-born lawyer, appointed justice minister in Canadian province". TheCable. 2020-08-26. Retrieved 2020-08-27. 
  3. "Obi hails Kaycee Madu on new appointment". The Sun Nigeria. 2020-08-27. Retrieved 2020-08-27. 
  4. Derek Van Diest Updated: April 16, 2019. "Results: Kacyee Madu wins Edmonton-South West in tightly contested battleground". Edmonton Journal. Retrieved 2019-04-17.