Moji Afolayan: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ẹ̀ka; Àdàkọ:Igbesiaye
Ìlà 27: Ìlà 27:
==Àwọn Ìtọ́kasí==
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
{{Reflist}}

{{Igbesiaye|1969||Afolayan, Moji}}
[[Ẹ̀ka:Àwọn òṣeré ará Nàìjíríà]]

Àtúnyẹ̀wò ní 14:21, 25 Oṣù Kẹ̀sán 2020

Mojí Afọláyan
Ọjọ́ìbí(1969-02-05)5 Oṣù Kejì 1969
Ibadan, Oyo, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • osere
  • filmmaker
  • producer
  • director
  • dramatist
Olólùfẹ́Rasaq Olayiwola
Parent(s)Ade Love (father)
Àwọn olùbátanKunle Afolayan (brother)
Gabriel Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)

Mojí Afọláyan tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1969 (February 5, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá láti ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Mojí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ bíbí olóògbé òní-sinimá àgbéléwò Adéyẹmí Josiah Afọláyan[2] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀. Mojí Afọláyan fẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Razaq Ọláyíwọlá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Òjòpagogo. [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Why my husband stays at home to nurse the kids-Moji Afolayan". The Nation Newspaper. Retrieved 27 February 2015. 
  2. "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2015-02-28. Archived from the original on 2015-02-28. Retrieved 2019-12-31.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Latest Nigeria news update". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2018-09-03. Retrieved 2019-12-31.