Esther Audu: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{short description|Nigerian actress}} {{Infobox person |name = Esther Audu |image = Esther Audu Watch Apartment 24.png |imagesize = 250 |caption = E..."
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 22:09, 25 Oṣù Kẹ̀wá 2020

Esther Audu
Esther in Apartment 24
Ọjọ́ìbíEsther James Audu
March 22, 1986 (1986-03-22) (ọmọ ọdún 38)
Ikeja, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Jos BA in Business Management
Iṣẹ́Actress

Esther Ene Audu tí wọ́n bí ní ọjó Kejìlélógún oṣù Keta ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] She is popularly known for starring in the films Dinner (2016), Mystified (2017) and Order of the Ring (2013).

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀tò ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Esther ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù Kẹ́ta ọdún 2986, sí inú ẹbí òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì nílé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà kan ọ̀gbẹ́ni James Audu . Bàbá rẹ̀ lo gbogbo ayé rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ekó ní inú bárékè ológun tí ó wà ní ìlú Ìkẹjà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé Ọmo bíbí ìlú Olamaboro ní Ìpínlẹ̀ Kogi ni wọ́n. Esther ni ó jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn ọmọ márùn ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìpínlẹ̀ Èkó àmọ́ òun ati àwọn òbí rẹ̀ kó lọ sí ìlú Àbújá ní ọdún 2002, tí ó sì lọ parí ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ níbẹ̀. Lẹ́yìn ilé-ẹ̀kọ́ girama, ó wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Jos ní Ìpínlẹ̀ Plateau láti kẹ́kọ́ gbawé érí ní inú ìmọ̀ Business Management ní ọdún 2006 tí ó aì jáde ní ọdún 2010.[2]

Iṣẹ́ rẹ̀

Esther bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré orí-ìtàgé síṣe láti ìgbà tí ó ti wà ní ilé-ékọ́ girama tí ó sì ma ń ṣojú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ níbi eré oníṣẹ́ ìtà gbangba. Ní ọdún 1996, ó wà lára àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ tí wọ́n yàn láti.ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ìdíje Kidafest ní orílẹ̀-èdè Gánà. Látàrí èyí, ó di ẹni tí ó nífẹ́ sí láti máa ṣeré dá àwọn ènìyàn lára yá. Ó kọ́kọ́ kópa nínú eré Ungodly romance and Sins of Racheal in Jos, eré tí Alex Mouth kọ. Esther fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eré yí ni ó jẹ́ kí òun láńfàní láti di òṣèré Nollywood lóní. Ó tún kópa nínú àwọn eré bíi: Fatal Mistake .[2]

Ìgbé ayé rẹ̀

Ó ṣe ìg ìyàwó pẹ̀lú ògbẹ́ni Philip Ojire tí ó jẹ́ oníṣòwò. [3][4]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

Ọdún Eré Ipa tí ó kó Notes
Ungodly Romance
Sins of Rachael
Fatal Mistake
2009 Behind a Smile
2010 Best Interest
2010 Best Interest
2012 Two Hearts
Royal Grace
Judas Game
Bachelors Hearts
2013 Return of The Ring
2016 Dinner
2017 Mistified

Awards and nominations

Àw ìtọ́kasí

Ìtàkùn ìjásóde

Àdàkọ:Authority control