Ṣàngó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 3: Ìlà 3:
Sàngó
Sàngó


Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ile e Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbògíì laarin àwon òrìsà tókù ní ilè e Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbo pe sàngó je télè kí ó tó di òrìsà ààrá. Itan so wipe omo Òrányàn ni sangó i se ati pe Oya, Òsun ati Obà je iyawo re.
Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ile e Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilè e Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ sàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.


Ìhùwàsì búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayée-fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bi Oba to bee titi ó fi òtéyímiká. Èyí jásí wípé tomodé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwo re kan tókù náà sì di odò.
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé Oba bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.


Ogbón tí àwon ènìyàn sàngó tókù dá láti fi bá àwon òtá rè jà nípa títí iná bolé won àti béèbéè lo ni ó so sàngó di òrìsàwon ń bo títí dòní tí wón sì ńfi enu won tuba wípé sangó kòso: Oba koso.
Ogbón tí àwon ènìyàn sàngó tókù dá láti fi bá àwon òtá rè jà nípa títi iná bolé won àti béèbéè lo ni ó so sàngó di òrìṣàwọ́n ń bo títí dòní tí wón sì ńfi enu won túúbá wí pé sàngó so: Oba koso.


ÀWON ORÚKO TÍ SÀNGÓ Ń JÉ
ÀWON ORÚKO TÍ SÀNGÓ Ń JÉ


Orísirísí orúko ni a mò sàngó nínú èyí tí gbogbo won sì ní ìtumò tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè béè. Àwon oniko bii ìwònyìí.
Oríṣiríṣi orúko ni a mọ sàngó nínú èyí tí gbogbo won sì ní ìtumò tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n béè. Àwon orúko bíi ìwònyìí:


1. Olukoso: Enití a mò mo kòso tàbí oba tí ó wolè sí kòso.
1. Olúkòso: Ẹnití a mò mọ́ kòso tàbí oba tí ó wolè sí kòso.


2. Arèfúnjayé:
2. Arèkújayé:


3. Àjàlájí:
3. Àjàlájí:
Ìlà 21: Ìlà 21:
4. Ayílègbe Òrun:
4. Ayílègbe Òrun:


5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirè, òun ni ó sì máa ńsàféérí nígbà ayé rè. Orógbó náà sì ni a maa nlo ni ojúbo saàngó titi di onì.
5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirè, òun ni ó sì máa ń ṣàféérí nígbà ayé rè. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbo sàngó títí di òní.


6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyè: Orisa tí ó máa ńfi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyè: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.


7. Onibon òrun: gégé bí òrìsà ó ń mú kí ààrá sán wá lati ojú òrun pèlú ìrókèkè tó lágbára.
7. Onibon òrun: gégé bí òrìsà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú òrun pèlú ìrókèkè tó lágbára.


8. Jàkúta: gégé bí orisanfi òkúta jà (edun ààrá). Irufe òkúta kékeré kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasè sàngó
8. Jàkúta: gégé bí òrìṣàń fi òkúta jà (edùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékeré kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ sàngó


9. Abotumo-bí-owú: Òrìsà o lee wole pa eniyan baje bi eni pe eru nla ni o wolu iru eni bee.
9. Abotumo-bí-owú: Òrìsà léè wolé pa ènìyàn bi eni pé erù ń ni ó wólu irú eni bẹ́ẹ̀.


10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irufe Orisa ti o je wipe ìsowó-sekupa asebii re maa ńya ènìyàn lénu gidigidi.
10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà ó jẹ́ pé ìṣowó-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lénu gidigidi.


11. Alágbára-inú-aféfé: Òrìsà tí ó jé wípé owoja a re, máa ńwá láti inú aféfé tàbí òfurufú ni.
11. Alágbára-inú-aféfé: Òrìsà tí ó jé wípé owọ́jà a re, máa ńwá láti inú aféfé tàbí òfurufú ni.


12. Abánjà-majebi: òrìsà tíí jà láì sègbè léhìn asebi tàbí se àsìmú elòmíràn fún onísé ibi.
12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè léyìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣé ibi.


13. Lánníkú-oko-oya: Òrìsà tí o ni èrù iku níkàwóó.
13. Lánníkú-oko-oya: Òrìsà tí o ni èrù iku níkàwó.


14. Òkokonkò èbìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukolè.
14. Òkokonkò èbìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukọlè.


15. Eléèmò: Òrìsà tí ó ni èèmò.
15. Eléèmò: Òrìsà tí ó ni èèmò.

Àtúnyẹ̀wò ní 10:26, 13 Oṣù Kínní 2007

Sango

Sàngó

Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ile e Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilè e Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé sàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti pé Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.

Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bí Oba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.

Ogbón tí àwon ènìyàn sàngó tókù dá láti fi bá àwon òtá rè jà nípa títi iná bolé won àti béèbéè lo ni ó so sàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bo títí dòní tí wón sì ńfi enu won túúbá wí pé sàngó kò so: Oba koso.

ÀWON ORÚKO TÍ SÀNGÓ Ń JÉ

Oríṣiríṣi orúko ni a mọ sàngó sí nínú èyí tí gbogbo won sì ní ìtumò tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n béè. Àwon orúko bíi ìwònyìí:

1. Olúkòso: Ẹnití a mò mọ́ kòso tàbí oba tí ó wolè sí kòso.

2. Arèkújayé:

3. Àjàlájí:

4. Ayílègbe Òrun:

5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirè, òun ni ó sì máa ń ṣàféérí nígbà ayé rè. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbo sàngó títí di òní.

6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyè: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.

7. Onibon òrun: gégé bí òrìsà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú òrun pèlú ìrókèkè tó lágbára.

8. Jàkúta: gégé bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (edùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékeré kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ sàngó

9. Abotumo-bí-owú: Òrìsà léè wolé pa ènìyàn bi eni pé erù ń lá ni ó wólu irú eni bẹ́ẹ̀.

10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣowó-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lénu gidigidi.

11. Alágbára-inú-aféfé: Òrìsà tí ó jé wípé owọ́jà a re, máa ńwá láti inú aféfé tàbí òfurufú ni.

12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè léyìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣé ibi.

13. Lánníkú-oko-oya: Òrìsà tí o ni èrù iku níkàwó.

14. Òkokonkò èbìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukọlè.

15. Eléèmò: Òrìsà tí ó ni èèmò.

AWON IWE ITOKASI

1. Daramola Olu [1967] Awon Asa ati Orisa Ile Yoruba. Lati owo Olu Daramola ati jeje Adebayo

2. Adeoye C. L. [1985] Igbagbo ati Esin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press