Imú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Imú jé èyà ara tí ènìyàn àti òpòlopò eranko fi n gbórùn. Gbígbó òórun wúlò fún ìgbádùn(gbigborun lofinda tàbí oúnje tó ní oòrùn tó dùn lé mú inú ènìyàn tàbí eranko dùn) ati ìkìlò ewu(bi apere; gbigbo oòrùn gaasi ti óún jò, gbígbó oòrùn eranko apanirun). Ihò inú imú jé ònà tí èémí ngbà wolé sínú ènìyàn ati òpòlopò eranko, o si tún jé ònà tí èémí ngbà jade.

Imú
Àwọn ajá ní imú tó kanra
Latin Nasus



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]