Mikhail Bakhtin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mikhail Bakhtin

Mikhail Mikhailovich Bakhtin (Rọ́síà: Михаил Михайлович Бахти́н, pípè [mʲɪxʌˈil mʲɪˈxajləvʲɪtɕ bʌxˈtʲin]) (November 17, 1895, Oryol – March 7, 1975) je ara Rosia amoye, oluyewo mookomooka, onimo semiotiki[1] ati omowe to sise lori iro mookomooka, ethics, ati imoye ede. Awon iwe re lori orisirisi ori-oro je eko fun awon omowe to unsise lori orisirisi eko (Isemarksi, Semiotiki, isedopo, iseayewo esin) ati lori eko bi iseayewo mookomooka, itan, imoye, oro-eda ati oroinuokan. Botilejepe Bakhtin je alakitiyan ninu awon ijiyan lori aesthetics ati litireso to sele ni Rosia Sofieti ni 1920, ipo re pato ko gbajumo titi ti awon omowe ara Rosia titunwari ni ewadun 1960.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Maranhão 1990, p.197