Jump to content

Robert Greene (American author)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Other people Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates Àdàkọ:Advert

Robert Greene
Ọjọ́ ìbí14 Oṣù Kàrún 1959 (1959-05-14) (ọmọ ọdún 65)
Los Angeles, California, U.S.
Iṣẹ́Author
Notable works
PartnerAnna Biller

Robert Greene (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1959) jẹ́ oǹkọ̀wé ọmọ Amẹ́ríkà tí ó kọ ìwé nípa strategy, power, àti seduction.[1][2] Ó ti kọ oríṣiríṣi ìwé tí wọ́n tà wàràwàrà káàkiri àgbáyé, lára wọn ni Òfin Méjìdínláàádọ́ta Agbára, The Art of Seduction, The 33 Strategies of War, The 50th Law (with rapper 50 Cent), Mastery, àti The Laws of Human Nature.[3]

Greene fìgbà kan sọ wípé òun kì í tẹ́lẹ̀ gbogbo ìmọ̀ràn tí wọ́n bá gba òun, wípé ẹnikẹ́ni tí ó bá gba òun ní ìmọ̀ràn lè banújẹ́ lọ́dọ̀ òun."[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]