Romário Leitão
Ìrísí
Romário Martins Leitão (ti wón bi ni ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kìíní ọdún 1997) jẹ asare gígùn nínú àwọn ìdíje Olympic lati São Tomé ati Príncipe . Ó kópa nínú eré ìdíje Olympic Ìgbà Òtútù ti ọdún 2016 nínú ìdíje oní 5000 mítà àwọn ọkùnrin, níbi tí ó ti parí ní ipò Kàrúndínlógbòn nínú eré ìje na.[1]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Romario Leitao". Rio 2016. Archived from the original on August 20, 2016. Retrieved August 19, 2016.