Jump to content

Rosalie Gangué

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Rosalie Gangué (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún, ọdún 1975) jẹ́ eléré Asáré àárín-ìjìnnà tí ó díje fún orílẹ̀ èdè Chad ní àgbáyé. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó ṣojú fún Chad nínú ìdíje Olympic.

Gangué ṣojú fún orílẹ̀ èdè Chad níbi ìdíje Olympic Ìgbà Òtútù ọdún 1992 ní Barcelona. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún ni. Ó kópa nínú ìdíje ti o ni 800 mítà ṣùgbọ́n kò parí ìdíje rẹ̀, ó tún kópa nínú ìdíje ti o ní 1500 mítà níbi tí ó ti parí ní ipò kẹwàá nínú ìdíje na, nítorí náà kò yẹ fún ìdíje tó tẹ̀lé e. [1]

  1. ↑ "Rosalie Gangue". sports-reference.com. Sports Reference LLC. Archived from the original on 18 April 2020. Retrieved 6 December 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)