Roseline Sonayee Konya
Ìrísí
Roseline Sonayee Konya | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Khana, Rivers State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | |
Gbajúmọ̀ fún | Rivers State Commissioner for Environment Toxicology and Pharmacology |
Notable work | SEARCHING THE SOUL OF THE ENVIRONMENT, WHO DARE? TERRITORIANS OR SUBDUERS? |
Roseline Sonayee Konya jé olóṣèlú láti Khana, ní ìpínlè Rivers. Ó jẹ ọ̀jọ̀gbọ́n Toxicology and Pharmacology ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Port Harcourt.[1][2] ó ṣiṣẹ́ àwọn aláṣẹ fún àyíká[3] ní ilé ìgbìmọ̀ ti Gómìnà Peter Odili wọ́n sì tún yàn sí ipò aláṣẹ ilé ìgbìmọ̀ ti Gómìnà Ezenwo Nyesom Wike.[4] Ó sì tún jẹ́ Alága fún ìgbìmọ̀ iṣẹ́ ìjọba ní ọdún 1997.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Konya Calls For Environmental Stewardship In Nigeria". University of Port Harcourt. Archived from the original on 30 April 2016. Retrieved 17 June 2016.
- ↑ Davies Iheamnachor (28 April 2015). "Toxicologists raise alarm over pollutants in N-Delta communities Calls". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2015/04/toxicologists-raise-alarm-over-pollutants-in-n-delta-communities/. Retrieved 17 June 2016.
- ↑ "'Government agencies, others fuelling air pollution in Port Harcourt'". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-27. Retrieved 2022-04-07.
- ↑ John Ighodaro (4 April 2005). "Odili Sets Up Committee to Study Ataba Crisis Report". Vanguard. http://allafrica.com/stories/200504041179.html. Retrieved 17 June 2016.
- ↑ "Konya Roseline". LitCaf (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-20. Retrieved 2022-03-21.