Salawa Abeni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Salawa Abeni
Birth name Salawa Abeni Alidu
Born Oṣù Kàrún 5, 1961 (1961-05-05) (ọmọ ọdún 56)
Ẹ̀pẹ́ Ìlú Èkó
Origin Ẹ̀pẹ́
Genres Orin wákà
Occupations Akọrin
Years active (1975 di àkókò yìí)

Salawa Abeni Alidu (ọjọ́ karún oṣù karún 1961) jẹ́ gbajúgbajà olórin ní ilẹ̀ Yorùbá.[1] Ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ orin kíkọ̀ ní ọmọ ọdún mẹ́jọ. O ṣe rẹ́kọ́dù Late General Murtala Ramat Mohammed jáde ní ọdún 1977, ó sì ti ṣe rẹ́kọ́ọ̀dú méjìlá jáde pẹ̀lú èyí tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Indian Waka" ní ọdún 1984.[2]

Àwọn orin tó ti kọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Late Murtala Muhammed (Leader, 1976)
 • Iba Omode Iba Agba (Leader, 1976)
 • Shooting Stars (Leader, 1977)
 • Ijamba Motor (Leader, 1978)
 • Okiki Kan To Sele/Yinka Esho Esor (Leader, 1979)
 • Orin Tuntun (Leader, 1979)
 • Irohin Mecca (Leader, 1980)
 • Ile Aiye (Leader, 1980)
 • Omi Yale (Leader, 1980)
 • Ija O Dara (Leader, 1981)
 • Ikilo (Leader, 1981)
 • Enie Tori Ele Ku (Leader, 1982)
 • Challenge Cup ’84 (Leader, 1983)
 • Adieu Alhaji Haruna Ishola (Leader, 1985)
 • Indian Waka (Kollington, 1986)
 • Ife Dara Pupo (Kollington, 1986)
 • Mo Tun De Bi Mo Se Nde (Kollington, 1986)
 • Awa Lagba (Kollington, 1987)
 • Abode America (Kollington, 1988)
 • Ileya Special (Kollington, 1988)
 • I Love You (Kollington, 1988)
 • We Are The Children (Kollington, 1989)
 • Maradonna (Kollington, 1989)
 • Candle (Kollington, 1990)
 • Experience (Alagbada, 1991)
 • Congratulations (Alagbada, 1991)
 • Cheer Up (Alagbada, 1992)
 • Waka Carnival (Alagbada, 1994)
 • Beware cassette (Sony, 1995)
 • Live In London ’96 cassette (Emperor Promotions, 1996)
 • Appreciation cassette (Sony, 1997)
 • with Barrister Evening Of Sound cassette (Zmirage Productions, 1997)
 • Good Morning In America (Alagbada, 1999)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Denselow, Robin (2001-07-20). "Queen Salawa Abeni". The Guardian. https://www.theguardian.com/culture/2001/jul/20/artsfeatures10. Retrieved 23 January 2010. 
 2. "Queen Salawa Abeni Biography". allmusic.com. Retrieved 30 April 2017.