Jump to content

Salome Makamba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Salome Makamba

Member of Parliament
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
November 2020
AsíwájúSpecial Seats
Arọ́pòSpecial Seats
ConstituencyWomen Rep
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Salome Wycliffe Makamba

18 Oṣù Kejì 1987 (1987-02-18) (ọmọ ọdún 39)
Shinyanga Region, Tanzania
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCHADEMA
EducationUhuru Secondary School
Kowak Girls' Secondary school
Alma materTumaini University

Salome Wycliffe Makamba (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejì ọdún 1987) Ó jẹ́ olóṣèlú ará Tanzania àti ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú CHADEMA. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ àwọn ìjókòó pàtàkì gẹ́gẹ́ bí aṣojú àwọn obìnrin, ó sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdú2020.