Jump to content

Segun Atere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Segun Atere
Personal information
OrúkọOluwasegun Atere
Ọjọ́ ìbí2 Oṣù Kọkànlá 1985 (1985-11-02) (ọmọ ọdún 40)[1]
Ibi ọjọ́ibíIbadan, Nigeria
Ìga1.75 m
Playing positionMidfielder
Youth career
Shooting Stars
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
2004–2005Gent2(0)
2005→ KFC Evergem-Center (loan)
2005–2007KFC Evergem-Center
2007–2013Kwara United
2014–2016Giwa
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Oluwasegun Atere (tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kọkànlá ọdún 1985) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù àárín gbùngbùn.

Iṣẹ́ Ìṣe Gégébí Agbábóólù

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Atẹ́rẹ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bọ́ọ̀lù gbígbá rẹ̀ pẹ̀lú ikọ̀ ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ agbábọ́ọ̀lù Shooting Stars ní ìlú Ibadan ní ọdún 2000, kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ikọ agba-ọjẹ egbẹ agbabọọlu naa ni oṣù Keje ọdún 2003. Ó dara pọ̀ mọ́ ikọ agbábọ́ọ̀lù Jupiler League ní K.A.A. Gent pẹ̀lú àdéhùn olódún méjì, ní oṣù kinni ọdún 2005. ó kó lọ sí ẹgbẹ́ agbábóòlù K.F.C. Ni Evergem ní àyán.[2] Ó gbá bọ́ọ̀lù fún ọdún méjì àti oṣù mẹ́fà pẹ̀lú ẹgbẹ́ náà kí ó tó padà sí orílẹ̀-èdè rẹ̀, ó sì fọwọ́ sí ìwé pẹ̀lú Kwara United F.C. Ó fọwọ́ sí ìwé pẹ̀lú àwọn olùbẹ̀rẹ̀ NPFL Giwa FC ní ọdún 2014.[3]

Iṣẹ́ Ìṣe Gégébí Agbábóólù kárí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Atere gbá bọ́ọ̀lù nínú ẹgbẹ́ awọn Golden Eaglets tí wọ́n gba àmì-ẹ̀yẹ wúrà aṣeyọrí agbáyé ti awọn Ọmọ-ọdún metadinlogun ní Seychelles ní ọdún 2001. Ó tún wà nínú ẹgbẹ́ U-20 orílẹ̀-èdè ní ọdún 2002 nígbà tí ó wà ní El-Kanemi, ó sì wà nínú ẹgbẹ́ U-23 tó gba ipò kejì ní awọn eré gbogbo Áfíríkà ti ọdún 2003 tí Nàìjíríà gbàlejò.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ "Segun Atere". worldfootball.net (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). HEIM:SPIEL Medien GmbH & Co. KG. Retrieved 5 July 2024.
  2. ↑ "African transfer round-up". February 2005. https://news.bbc.co.uk/sport2/hi/football/africa/4226677.stm.
  3. ↑ "Atere joins Giwa FC".