Segun Johnson
Ìrísí
Segun Johnson jẹ́ olórin ìgbàlódé tàkasúfèé orí ìtàgé [1][2] ọmọ bíbí ìlú Ẹ̀pẹ́ l'órílẹ̀-èdè Nigeria. Wọ́n bí Ṣẹ́gun Johnson ní Òkè-Irà, ní Ọgbà, Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó jẹ́ ọmọ tí ìyá dá tọ́. Búrẹ́dì ni ìyá rẹ̀ ń tà fi tọ́ ọ.[3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Reporters, Our (2023-06-17). "Singer Segun Johnson reveals secret behind his unique style". Punch Newspapers. Retrieved 2024-12-07.
- ↑ Ajose, Kehinde (2023-02-19). "Segun Johnson surprised at cash gift from Naira Marley". Punch Newspapers. Retrieved 2024-12-07.
- ↑ Ojoye, Taiwo (2019-01-06). "Being bread seller’s son spurs me on –Segun Johnson". Punch Newspapers. Retrieved 2024-12-07.
- ↑ "Segun Johnson: I Grew Up As Son of a Local Bread Seller – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. 2019-03-16. Retrieved 2024-12-07.