Jump to content

Sitanda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Sitanda
Fáìlì:Sitanda poster.jpg
AdaríIzu Ojukwu
Olùgbékalẹ̀Amstel Malta
Àwọn òṣèré
OrinDaps
Déètì àgbéjáde
  • 2006 (2006) (Nigeria)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish

Sitanda jẹ́ fíìmù ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2006, èyí ti olùdarí rẹ̀ jẹ́ Ali Nuhu tó gba Àmì-ẹ̀yẹ ti Arica Movie Academy Awards nígba kan rí. Orúkọ òǹkọ̀tàn fíìmù yìí ni Fidel Akpom. Fíìmù náà gba ìyàn fún àmì-ẹ̀yẹ mẹ́sàn-án, tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ márùn-ún nínú mẹ́san-án tí wọ́n yàn án fún ní ọdún 2007, ní ayẹye Africa Movie Academy Awards, ti ẹlẹ́ẹ̀kẹta rẹ̀. [1] [2] [3]

  • Ali Nuhu bíi Sitanda
  • Stephanie Okereke bíi Ann
  • Azizat Sadiq bíi Sermu
  • Ireti Doyle bíi Princess
  • Justus Esiri bíi Papa Ann
  • Bimbo Manuel bíi Amanzee
  • Fidelis Abdulrahman bíi Ebule
  • Wale Adebayo bíi Kidnapper
  • Ife Adejo bíi Nọọsi Abule
  • Tolu Daniel Aluko bíi Sitanda nígbà ọ̀dọ́ rẹ̀
  • Segun Alagbe bíi Slave Guard
  • Sunday Eze bíi Alagba
  • Augusta Isaac bíi Queen
  • Tina Ofikwu bíi Mama Ann

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Africa Celebrates Film Industry at AMAA 2007". Minneapolis, USA: Mshale Communications. Archived from the original on 3 March 2012. https://web.archive.org/web/20120303204433/http://www.mshale.com/article.cfm?articleID=1407. 
  2. Empty citation (help) 
  3. Nollywood: the video phenomenon in Nigeria. Indiana University Press. https://books.google.com/books?id=ZhwqAQAAIAAJ.