Jump to content

Stella Ngwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Stella Ngwu
Member of the
House of Representatives of Nigeria
In office
2011–2015
In office
2015–2019
Arọ́pòMarthins Oke
ConstituencyIgbo-Etiti/Uzo-Uwani Federal Constituency
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí9 Oṣù Keje 1958 (1958-07-09) (ọmọ ọdún 67)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP
ProfessionPolitician

Stella Uchenwa Obiageli Ngwu ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án osù keje ọdún 1958. Ó jé̩ olóṣèlú ọmọ orílè̩-èdè Nàìjíríà làti Ìpínlẹ̀ Enugu. Ọmọ bibi ìlù Ukehe ni ìjọba ìbílẹ̀ Igbo-Etiti ni Ìpínlẹ̀ Enugu. O ṣe aṣoju àgbègbè Igbo-Etiti/Uzo-Uwani ni ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà orílè-èdè Nàìjíríà. [1] lati ọdun 2011 si ọdún 2019 labẹ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party . [2] [3] Ni ọdun 2016, Ile ejò ìjọba àpapọ̀ ti ìlú Abuja le e kuro ni Ile-igbimọ aṣòfin ṣugbọn o bori ninu ìbò atundi ni ọdun 2017. [4]