Stella Uchenwa Obiageli Ngwu
Ìrísí
Stella Uchenwa Obiageli Ngwu tí a bí ní ọjọ́ kẹsan-an,oṣù keje ọdún 1958 tí o tún jẹ́ òkan lára àwọn olóṣèlú orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ìpínlẹ̀ Enugu. Ọmọ bíbí ìlú Ukehe ní Igbo-Etiti,ìjọba ìbílẹ̀ ti Enugu. Ó ṣojú ìjọba àpapò ti Igbo-Etiti/Uzo-Uwani ní ilẹ̀ ìgbìmò aṣojú ṣòfin láti ọdún 2011 di ọdún 2019 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP). Ní ọdún 2016, ilé ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ ti ìpínlẹ̀ Abuja da dúró nínu ilé sùgbọ́n o jáwé olúborí nínu ìdìbò ti ọdún 2017. [1]
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Onochie, Bridget Chiedu (19 October 2016). "Court sacks Enugu House of Reps' members". Guardian. https://guardian.ng/news/court-sacks-enugu-house-of-reps-members/. Retrieved 22 November 2020.