Sékou Touré

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ahmed Sékou Touré
President Ahmed Sékou Touré of the
Republic of Guinea arrives at Andrews
Air Force Base
in Maryland during a visit
to Washington DC. (June 1982)
1st President of Guinea
In office
October 2, 1958 – March 26, 1984
AsíwájúNone (position first established)
Arọ́pòLouis Lansana Beavogui
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1922-01-09)Oṣù Kínní 9, 1922
Faranah, French Guinea
AláìsíMarch 26, 1984(1984-03-26) (ọmọ ọdún 62)
Cleveland, Ohio,
United States
Ọmọorílẹ̀-èdèGuinean
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Party of Guinea

Ahmed Sékou Touré (bamiran Ahmen Seku Ture) (January 9, 1922 – March 26, 1984) je asiwaju oloselu ara Afrika ati Aare orile-ede Guinea lati odun 1958 titi di ojo iku re ni odun 1984. Touré je enikan pataki larin awon asetomoorile-ede Guinea ti won kopa ninu igbominira orile-ede na lowo France.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Sékou Touré je bibi ni January 9, 1922 sinu ebi awon eniyan Mandinka ni Faranah, French Guinea, lasiko tibe je ohun alamusin ile Fransi. He was an aristocratic member of the Mandinka ethnic group[1] and was the great-grandson of the famous Samory Touré,[2], who had resisted French rule until his capture.

Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2021, ni akoko ayẹyẹ 50th ti ipakupa Oṣu Kẹwa ọdun 1971, awọn ibatan ti 70 Guineans ti o pa labẹ ijọba Sékou Touré beere lọwọ Alakoso Mamady Doumbouya fun isọdọtun ati isinku ti o ni ọla fun awọn olufaragba naa.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. RADIO-KANKAN: La premiere radio internet de Guinée-Conakry: GUINEE: RADIO-KANKAN
  2. Webster, James & Boahen, Adu (1980), The Revolutionary Years; West Africa since 1800, p. 324.