Jump to content

Temi Harriman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Temi Harriman''' ( a bí i ní ọjọ́ kinní osù kinní ọdún 1963) jẹ́ agbẹjọ́rò, olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, ó sí jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin tó ń sójú ìpínlẹ̀ Warri lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú APP. [1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti iṣẹ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣojú sòfin fún ìpínlẹ̀ Warri lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú APP láti 1999 sí 2003. Ó sì tọ́jú ìjókòó rẹ̀ fún sáà mìíràn láti ọdún 2003 sí 2007. [2]

  1. Admin (2017-02-20). "HARRIMAN, Hon. Temi". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-01. 
  2. "Public offices held by Temi Harriman in Nigeria". citizensciencenigeria.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-01. 

Ẹka:Àwọn Obìnrin Nàìjíríà