Jump to content

Tijani Kayode Ismail

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tijani Kayode Ismail
Member of the House of Representatives (Nigeria)
from Oyun Local Government
ConstituencyOffa/Oyun/Ifelodun
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹta 1983 (1983-03-27) (ọmọ ọdún 42)
Erin-Ile,Oyun Local Government Kwara State Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
Alma mater
Occupation
  • Politician

Tijani Kayode IsmaI ( ọjọ́ keji oṣù kẹta ọdún 1983) jẹ olóṣèlú ọmọ orile-ede Nàìjíríà ti o nsójú àgbègbè Offa/Oyun/Ifelodun ni ile ìgbìmò aṣòfin àgbà ni Abuja lati Ìpínlè Kwara ni Apejọ Kẹsán ati kẹwàá. [1] O dije, o si gba tikẹẹti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) Ile-igbimọ Aṣoju (Nigeria) ni ọdun 2019 o si ṣe aṣeyọri fun igbákejì lasiko ìdìbò gbogbogbòò ọdún 2023. [2] [3]