Tim Berners-Lee
Appearance
Timothy Berners-Lee | |
---|---|
Berners-Lee, London, 2014 | |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹfà 1955[1] London, England[1] |
Ibùgbé | Massachusetts, USA[1] |
Orílẹ̀-èdè | British |
Ẹ̀kọ́ | The Queen's College, Oxford |
Iṣẹ́ | Olusesayensi Komputa |
Employer | World Wide Web Consortium and University of Southampton |
Gbajúmọ̀ fún | Inventing the World Wide Web |
Title | Professor |
Parent(s) | Conway Berners-Lee, Mary Lee Woods |
Website | w3.org/People/Berners-Lee |
Notes | |
Holder of the 3Com Founders Chair at MIT's Computer Science and Artificial Intelligence Laboratory |
Timothy John "Tim" Berners-Lee, OM, KBE, FRS, FREng, FRSA (born 8 June 1955[1], bakanna bi "TBL"), je onise-ero ati onimosayensi komputa ati ojogbon MIT ara Britani to je didalawin fun imdasile World Wide Web, nigba to dero re ni Osu Keta 1989.[2] Ni 25 Osu Kejila 1990, pelu iranlowo Robert Cailliau ati odo akeko kan ni CERN, o se ibanisoro ayorisirere larin ero ipe HTTP kan ati ero iwofa itakun lori Internet.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |