Tina Acketoft
Ìrísí

Tina Acketoft (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù Kẹta ọdún 1966 ní Kokkola, Finland) jẹ́ olóṣèlú ọmọ-ẹgbẹ́ Liberal People's Party ti orílẹ̀-èdè Sweden. Láti ọjọ́ kọkànlá oṣù Kìíní ọdún 2007 ni ó ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Riksdag, nígbà tí ó rọ́pò Torkild Strandberg. Acketoft ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ náà láti ọdún 2002 sí 2006.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Tina Acketoft (fp) Riksdagen" (in Swedish). Retrieved 2008-10-06.