Jump to content

Tobi Adegboyega

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pastor
Tobi Adegboyega
Ọjọ́ìbíTobi Adegboyega
11 Oṣù Kọkànlá 1980 (1980-11-11) (ọmọ ọdún 44)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaOgun State University
Iṣẹ́Pastor, televangelist
TitleFounder of SPAC Nation
Alábàálòpọ̀
Lucy Oluwatosin Odetola (m. 2011)
Àwọn olùbátanJohn Boyega (cousin)
Websitenxtionfamily.org/about-us

Tóbi Adégbóyèga (tí wọ́n bí lọ́jọ́ 11 oṣù November ọdún 1980) jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run ọmọ Nigeria.[1] Òun ni olùdásílẹ̀ ìjọ Salvation Proclaimers Anointed Church (SPAC Nation, tí a wá padà mọ̀ sí ìjọ NXTION Family), èyí ìjọ pentecostal àná[2] tó fìgbà kan wà ní London, lórílẹ̀-èdè England.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]